Àkọlé fídíò, 'Owó tí mo ń rí lórí Garri ni mo fi ń ran ọkọ lọ́wọ́'
Ogagun Abubakar ni ikọ omo ogun oriṣi meji ti wọn kọkọ gbe kalẹ lati gbogun ti ijinigbe ni yoo jọ lo ẹro yii lati mu ayipada de ba eto aabo awọn eniyan ipinlẹ Ondo ati Ekiti
Àkọlé fídíò, YSAN 2018: llú Ondo gbàlejò Àpérò Ẹgbẹ́ Onímọ̀ èdè Yorùbá Nàìjírìa
Ileeṣẹ ọmọ ogun ilẹ ni aja iwoyi lo mọ ehoro iwoyii lé ni awọn fi ọrọ yii ṣe.
O ni igbo kijikiji to wa ni agbegbe yii ni awọn kan ti sọ di ibuba wọn fun iṣẹ ibi.
Àkọlé fídíò, 'A máa ń bẹ́ orí ẹni tó bá gbé imọlẹ̀ ọdún ìjẹṣu tó bá ṣubú ni'
Ogagun Azinta to jẹ olori ikọ ọmọ ogun ni ẹkun yii ni wọn ti paṣẹ fun pe ko rii pe gbogbo ọmọ ogun sá ipa wọn fun alaafia awọn eniyan Ekiti ati Ondo ti wọn n gbe ninu ipaya bayii.
Àkọlé fọ́nrán ohùn, 'Igbe àwọn ọ̀dọ́ kọ́ ló mú wa pèsè iná l'Ondo'
Awọn ọmọ ogun wa fi da gbogbo awọn arinrinajo loju pe ko nii sewu mọ lopopona lati isinyii lọ.
Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ondo: Iya lu ọmọ pa nítori ẹgbẹ̀rún mọkànlélógun Naira
Wọn ni awọn ikọ tijọba ṣagbekalẹ lati gbogun ti awọn ajinigbe ti bẹrẹ iṣẹ ni pẹrẹwu ni agbegbe yii.
Àkọlé fídíò, Ondo: Dejí sun ọmọ méje àtagbalagba meji mọ́lé nítorí pé ó ń bínú
Igbagbọ awọn eniyan ipinlẹ Ondo ati Ekiti ni pe laipẹ ni wọn yoo le tun maa fẹdọ sori oronro sun bii ti tẹlẹ pẹlu igbesẹ tuntun ti awọn ọmọ ogun gbe yii.
Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ondo; 1000 si 2000 naira lowo ori ilẹ fun mẹkunu
Àkọlé fídíò, Ekiti Election: Ẹgbẹ́ awakọ̀ Ekiti pa ìjọba dà lẹ́yìn tí wọ́n kéde Fayẹmi