BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Fayemi: Àwọn àwòrán tó jẹ ojú ní gbèsè níbi ìbúra
16 Ọ̀wàrà 2018
Awọn awọran to joju ni gbese nibi ayẹyẹ iburawọle sipo Fayemi ni Ado Ekiti
Àkọlé àwòrán,
Awọn eeyan n duro ki ayẹyẹ naa bẹrẹ
Àkọlé àwòrán,
Awọn lọbalọba ko gbẹyin nibi ayẹyẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Oni nkan laa jẹ o ṣẹ e .Fayemi balẹ biba sibi ayẹyẹ iburawole
Àkọlé àwòrán,
Awọn Imamuu wa nibẹ lati fi adura ran ijọba tuntun yi lọwọ
Àkọlé àwòrán,
Ko si ayẹyẹ iburawọle ti ko ba si adajọ ti yoo bura fun Gomina tuntun
Àkọlé àwòrán,
Ogbeni Kayode Fayemi ati iyawo rẹ ni wọn jijọ kọwọrin wa ibi ayẹyẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Ki lẹ lero wi pẹ alagba Bisi Akande n sọ fun alaga ẹgbẹ APC teleri alagba John Odigie-Oyegun?
Àkọlé àwòrán,
Gbajugbaja osere Odunlade Adekola naa peju sibi ayẹyẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Igbakeji Gomina Otunba Bisi Egbeyemi ati Iyawo rẹ n yọ sẹṣẹ
Àkọlé àwòrán,
Gomina ipinlẹ Eko Akinwumi Ambode naa yọju
Àkọlé àwòrán,
Babajide Sanwoolu naa wa ba Kayode Fayemi yọ
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology