Nigeria 2019 Elections: INEC gbé orúkọ àwọn olùdíje fún ipò ààrẹ àti ilé aṣòfin jáde

Oríṣun àwòrán, INEC Situation room
Ajọ eleto idibo Naijiria (INEC) ti gbé orúkọ awọn oludije to kógojá lati dije ninu idibo gbogbogbo ti ọdun 2019 jade.
Àwọn orukọ to jade naa ni awọn oludije ipo aarẹ ti idibo wọn yoo waye ni ọjọ kẹrindinlogun oṣu keji ati ile igbimọ aṣofin agba oun ile aṣoju-ṣofin ti idibo wọn yoo waye ni ọjọ keji oṣu kẹta.
Orukọ oludije aarẹ mẹtalelaadọrin ni INEC gbe jade pẹlu awọn amugbalẹgbẹ wọn.

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC

Oríṣun àwòrán, INEC
Orukọ gbogbo awọn ti yoo dije fun ile igbimọ aṣofin agba wa ati aṣoju-ṣofin wa lori atẹ ayelujara INEC.








