Ẹ ti tọ APC àti PDP wo báyìí, ẹ dìbò fún olùdíje ẹgbẹ́ tí kò ni fi ayé ni yin lára- Akinwale Solomon Akinwole

Àkọlé fídíò, Ẹ ti tọ APC àti PDP wo báyìí, ẹ dìbò fún olùdíje ẹgbẹ́ tí kò fi ayé ni yin lára- Akinwale

Ẹ̀yin ara Oke Ogun ati Ogbomoso, ẹ fọkan balẹ, didun lọsan a so- Akinwale.

Honorebu Akinwale Solomon Akinwole ti ọpọ mọ si Wọlekanlẹ ni Ogbomoṣọ ni ipinlẹ Oyo lo ṣalaye kikun lara awọn ohunt o ti ṣe ṣeyin ati ohun to ni lọkan lati ṣe.

O mẹnuba idi ti oun ṣe n dije dupo Sẹnatọ lati ṣoju a\won eniyan Ariwa Oyo nipinle Oyo.

O sọrọ nipa ohun to ṣokunfa inagije wọlekanle ti oun n jẹ lataari pe agbabọọlu ni oun lati kekere.

Ni afikun, Akinwale gab awọn eniyan Naijiria niyanju lati dibo pẹlu alaafia, wọn ko gbọdọ ja tabi fa rogbodiyan kankan.

O tun salaye idi to ṣe fẹ ki wọn dibo fun oun ni Oke Ogun ati ni Ogbomoso.