Mother tongue day 2023: Catering $ Hotel ni mo kọ́ ṣùgbọ́n Ìfẹ́ tí mo ní sí àṣà, èdè, ìwà àti ìṣe Yorùbá ló mú mi lọ ṣiṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́
Ààyè wà fún ẹni tó bá ń ṣiṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ láti máa jókòó pẹ̀lú àwọn aláṣẹ orílẹ̀ èdè.
Yeyeluwa Ibiyemi Ajadi Aina Orosun ni agba ọjẹ pataki lara awọn agbohunsafefe agbalagba ni ilẹ̀ Yoruba.
Yeyeluwa pàrọwa fun awon Obinrin to ba fẹ yan iṣẹ igbohunsafẹfẹ laayo lati pa ọkan rẹ mo. ko ma ṣe ọlẹ, ko di eti ẹ si ahesọ ọrọ ko si di ile rẹ mu daadaa ki o le ṣasẹyóri lẹnu iṣẹ igbohunsafẹfẹ gẹgẹ bii obinrin.
- BBC Yorùbá gba àmì ẹ̀yẹ akọni nídìí àgbéga àṣà àti èdè abínibí
- Ọmọ tí wọ́n bá fi èdè Yorùbá kọ́ ní ẹ̀kọ́ máa ń pegedé jú tí èdè míràn lọ- Ọjọgbọn Ogundeji
- Ọwọ́ tẹ Nọ́ọ̀sì ọmọ Nàìjíríà 20 tó ń fi ayédèrú ìwé ẹ̀rí ṣiṣẹ́ ní US, bàa ṣe rí wọn mú rèé - Ìjọba
- Irọ́ ni awakọ̀ tó pa ẹbí Fatinoye ń pa pé wọn kò fún òun lówó, èyí tó ṣojú mi rèé...
- Wo àlàkalẹ̀ àwọn ìpèníjà tí Ààrẹ tó bá borí ní Nàìjíríà yóò dojú kọ
Yeyeluwa Ibiyemi Ajadi ni pe obinrin gbọdọ gab iyọnda ọkọ re ko to bẹrẹ iṣẹ naa nitori pe ọpọ ọkunrin kii fẹ ki aya wọn ṣe iṣẹ yii.
Agba ọjẹ igbohunsafẹfẹ yii mẹnuba awọn ipenija to wa lẹnu iṣẹ yii.
O sọ pataki kikọ ede Yoruba ki o dantọ ki ọmọ naa si gbọ ibawi ko le mọ iṣẹ igbohunsafẹfẹ sii.
- Bawo ni o ṣe mọ ede rẹ si?
- Yorùbá rẹwà, kọ́ nípa àwọn ọ̀rọ̀ tí ìró ẹnu wọn jọra àmọ́ tí ìtumọ̀ wọn yàtọ̀
- Àwọn olùkọ́ èdé Yorùbá l‘Eko dábírà ní àyájọ́ èdè abíníbí
- Ó ṣe mí ní àánú fún ọmọ Yorùbá tí kò le sọ èdè abínibí rẹ́ - Ọmọ Igbo Chukwuka
- Ọmọ tí wọ́n bá fi èdè Yorùbá kọ́ ní ẹ̀kọ́ máa ń pegedé jú tí èdè míràn lọ- Ọjọgbọn Ogundeji
Yeyeluwa Ibiyemi tun sọ diẹ lara ohun ti oju rẹ ri lẹnu iṣẹ igbohunsafẹfẹ paapaa laisko awọn ṣọja ologun ni Naijiria.
O tun sọ nipa ayọ to rọ mọ iṣẹ igbohunsafẹfẹ.
Bakan naa ni Yeyeluwa tun gab awọn ọkọ ti aya wọn n ṣiṣe igbohunsafẹfẹ ni imọran lati fi ifẹ ati ootọ inu ba ara wọn lo.