Michael Lana tí ẹgbẹ́ SDP sọ ǹkan tuntun mẹ́ta tó fẹ́ ṣe yàtọ̀ fún olùdìbò ìpínlẹ̀ Oyo níbi ìpàdé ìta gbangba BBC Debate
Ijọba Oyo ko na owo ilu sibi to dara fun ara ilu- Oludije SDP.
BBC Yoruba ṣeto ipade itagbangba ni ilu Ibadan nipinle Oyo ki awọn oludije le lanfaani lati wa ba awọn oludibo sọrọ lori ohun ti wọn fẹ ṣe fun ara ilu.
Amofin Michael Lana to n dije labẹ ẹgbẹ oṣelu SDP ba BBC Yoruba sọrọ lori ohun to ni lọkan lati se.
- Ọkọ̀ òfúrufú tó kó èèyàn 72 já lulẹ̀ ní Nepal, ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ṣòfò
- JJC Skillz, ọkọ Funke Akindele tẹ́lẹ̀ padà sínú ẹ̀sìn Islam, o ní Allah dáríjín mi!
- Àwọn agbébọn yabo ilé Àlùfáà, wọ́n sun òun àti ọ̀pọ̀ dúkìá mọ́lé
- Iṣẹ́ 'lecturer' ló wù mí ṣùgbọ́n ìdí mọ́káníìkì tírélà ni orí gbé mi lọ- Asabi Siyanbola
- Adéͅrìnpósͅónú Papa Ajasco ọdún 2005 sí 2006 ti jáde láyé
- Èrè tó pọ̀ ni gbogbo Oníṣòwò máa jẹ ní 2023- Imam Sabit Olagoke
- Ẹni bá láyà: Ṣé ìwọ mọ àmì Yorùbá dáadàa?

Michael Lana tun sọ ohun to fẹ sẹ lori eto ẹkọ ati eto ọgbin ipinlẹ Oyo pẹlu eto pataki fawọn Obinrin ipìnle Oyo.
O menuba ajọṣepọ oun ati Senato Adewolu Ladoja.