Imam ìjọ Shafaudeen in Islam, Sabit Olagoke gbàdúrà pé kò sí olólùfẹ́ BBC Yorùbá tó máa ṣìrìn lọ́dùn 2023

Àkọlé fídíò, Imam ìjọ Shafaudeen in Islam, Sabit Olagoke gbàdúrà pé kò sí olólùfẹ́ BBC Yorùbá tó máa ṣì

Ko si ẹni ti ko ni lu aluyọ lọla Eledua ni 2023 yii.

Bi ọdun 2023 ṣe ti wọle de wẹrẹ yii, BBC Yoruba kan si Imam agba ninu ijọ Mosalasi Shafaudeen In Islam lati sadura ọdun fun gbogbo ololufẹ BBC Yoruba pẹlu ilana musulumi.

Imam Sabiat Olagoke ni pe ayọ lo ku lọdun 2023.

Ati pe Allahurabi yoo fun ijọba Naijiria lọgbọn ati agbara lati ṣe ẹtọ to yẹ fun awọn oṣiṣẹ.