Bolaji Amusan: TAMPAN ń ṣiṣẹ́ lórí 'minimum wage àti insurance' òṣèré báyìí- Mr Latin
Ọpọ́ àwọn tó n tọrọ owọ lori ayelujara ni ẹgbẹ́ àti 'indicvidual'ti ràn lọ́wọ́- Latin
Aarẹ ẹgbẹ awọn oṣere ni Naijiria, Bolaji Amusan ti ọpọ mọ si Mr Latin gablejo BBC Yoruba.
Nibẹ lo ti sọrọ ni kikun lori pe awọn oṣere kọọkan n tọrọ owo lori ayelujara nigba ti wọn ba wa ninu iṣoro.
O mẹnuba ipa ti ẹgbẹ n ko lati ran awọn oṣere lọwọ.
- Kò sí owó nínú iṣẹ́ tíátà, mi ò sì ní bàbá ìsàlẹ̀ – Opeyemi Ayeola
- Messi fi ìtàn lélẹ̀, Ife ẹ̀yẹ àgbáyé di ti Argentina lẹ́yìn ọdún 36
- Russia-Ukraine war- Russia kó àwọn olórin sójú ogun láti ṣe kóríyá fáwọn ọmọ ogun
- INEC, kò sí ìdí kankan fún un yin láti má bẹ̀rẹ̀ ìgbáradì ètò ìdìbò báyìí- Buhari
- Pásìtọ̀ kan, olùkọ́ kan àti àwọn mẹ́ta míì dèrò iléẹjọ torí wọ́n fipá bá ọmọ ọdún 11 lò pọ̀

Bakan naa ni Mr Latin tun sọ nipa pataki ṣiṣe sinima ti yoo kọ awon eeyan lẹko ati pataki jijẹ ọmọluwabi gẹgẹ bi oṣere ni eyi ti ẹgbẹ fi n kọ won ni TAMPAN.
O tun sọrọ lori bi onikaluku ṣe n na owo rẹ lọtọọtọ pe oriṣii nakn to wu onikaluku lo n na owo rẹ si lawujọ.
O menuba ipa ti ẹgbẹ n ko lori eto adojutofo ati owo sisan fun awon oṣere.
- Ọjà Àgbáláta ní Badagry rèé, níbití ẹran ejò ti dùn ju ẹran adìẹ lọ
- 'Kí a tó lọ “Studio” lọ kọ orin “Odun nlo sopin”, a ju ara wa sínú àdúrà, bíbélì, ìmísí, ...'
- Ká sọ pé mi kò díje, n kò lè dìbò fún Obi àti Atiku nítorí pé wọn kò kúnjú òṣùwọ̀n tó- Tinubu
- Mo kọ̀ láti fí owó kó aya jọ ní mo ṣe lọ káwé láti LLB dé PhD ǹsìyìí lárúgbọ ara- Oba Ogunleye
- 'Ayé kọ́ ló ṣe mi tí ojú fi fọ́, àmọ́ bí mo ṣe ń fi ojú tó fọ lu gangan, tún -generator- ṣe kò yé mi'
- Islam àti ìfẹ́ tí mo ní sí ìlú ni mo fi fẹ́ kí wọ́n kà mí kún àwọn tó ń ṣe dáadáa - Salihu Mustapha APC
- Iṣẹ́ òpùrọ́ ni Olọ́run fi rán APC, wọn kò ṣiṣẹ́ ìlú kankan ní Kwara- Bolaji Abdullahi