Alaafin Stool: Orúkọ ọmọ oyè méjìsínlàádọ́ta ló ti wà láti yan Aláàfin Oyo tuntún nínú wọn

Oríṣun àwòrán, @Alaafin Oyo
Ni kete ti Oba Lamidi Adeyemi keta ti waja naa ni itẹ Oba Alaafin ti ilu Oyo ni guusu iwọ oorun Naijiria ti ṣi silẹ.
Lara awọn to lẹtọ si ipo Oba naa ni Biṣọọbu agba ijọ Eleto ti Methodist ni, Biṣọọbu agba Ayo Ladigbolu.
Biṣọọbu naa lo tile ni ẹni ọdun mérinlelogọrin bayii.
Awọn orukọ ọmọ oye ti aye n pariwo naa niyii:
OKE APO (GBADEGESIN):
1.Abdul Rashidi Adewale GBADEGESIN
2.Omowe Abidoye GBADEGESIN
3.Abdrasak Adegoke GBADEGESIN
4.Kabiru Adebayo GBADEGESIN
5.Isiak Olatunde GBADEGESIN
6.Basiru Adeniyi GBADEGESIN
7.Monjeed GBADEGESIN
8.Lukman Adelodun GBADEGESIN
9.Babajide Aderoju GBADEGESIN
10.Abdmonjeed Adekunle GBADEGESIN
ILAKA OLAWUWO:
11.Ajibade Adebayo ADELADAN
12.Tella Biliaminu KOLAWOLE
13.Tiani Hammed ADEBAYO
14.Salami Saheed BABATUNDE
15.Ladigbolu Adewale ADEREMI
16.Adekunle Mutahir ADEGBOYE
17.Alh. Tesleem Oriade LADIGBOLU
18.Adekunle Kamal ADEYEMI
19.Adebisi Jeleel ADENIYI
ISALE-OJA:
20.Oluokun Kasali AGUNLOYE
21.Adekunle Gafar ADEBAYO
22.Tella Meroof ADENIYI
23.Owoade Wahab Folorunso ADEREMI
24.Adewusi Mukaila OLANREWAJU
25.Olaide Dauda OLADIMEJI
26.Tella Adeniyi KAREEM
27.Agunloye Adelayo ADEREMI
28.Aderogba Idowu AGUNLOYE
29.Morounranti Hakeem ALAYOAYO
30.Gbadegesin Taofeek AGUNLOYE
31.Remilekun Enitan ADENIYA
32.Razak ALAYOAYO
33.Akinade Abdul Rahman ALAYOAYO
- "Kòríkòsùn lèmi àti Alaafin ṣùgbọ́n kété táwọn kan kẹ́ẹ́fín pé èmi láàyò ni gbogbo nǹkan dojúrú." Badirat Ajoke, olorì tẹ́lẹ̀ kẹ́dùn Alaafin
- Ta ni Yorùbá ń pè ní Abọ́bakú?
- Mọ̀ síi nípa Olorì Abibat Nihinlola Adeyemi tó ti lo ọdún 60 gẹ́gẹ́ bíi olorì láàfin Alaafin Oyo
- Alaafin Oyo tuntun yóò gorí ìtẹ́ láìpẹ́ - Makinde
- Ààrẹ Buhari, Ooni Ile Ife, Obasanjo kẹ́dùn Alaafin Oyo tó wàjà
LADIGBOLU:
34. Biṣọọbu Agba Omọọba Lawrence Sanda Ayo LADIGBOLU
35.Lukman Alabi Olugbenga LADIGBOLU
36.Hakeem Abiodun Adeyanju Ayinde LADIGBOLU
37.Ayobami Adewumi Sanda LADIGBOLU
38.Amidu Abiodun LADIGBOLU
39.Muideen Adekunle LADIGBOLU
40.Kolade Tunde Saani LADIGBOLU
41.Adegboyega Ibrahim LADIGBOLU
42.Abdulquadri Opeyemi LADIGBOLU
43.Ismaila Aderemi Belawu Adekunle LADIGBOLU
44.Adebimpe Wasiu Abiodun LADIGBOLU
45.Taofeek Adewumi LADIGBOLU
46.Rasaki Kamorudeen Osuolale LADIGBOLU
OWOADE AGURE:
47.Hakeem Babatunde Adetunji OWOADE
48.Ibrahim Abiodun Olayiwola OWOADE
Eyikeyi ninu awọn wọnyii ni wọn yoo pada yan gẹgẹ bii Alaafin Oyo tuntun ti yoo maa ṣakoso Oyo ni alaafia.
Ki Eledumare faaye gba ẹni ti asiko rẹ yoo tu tẹbi tara lara ni adura gbogbo iran Yoruba.












