Ekiti 2022: Kìí ṣe gómínà nìkan ni Ekiti nílò báyìí fún ọjọ́ ọ̀la tó dára- Oluwole Oluyede

Àkọlé fídíò, Ekiti 2022: Kìí ṣe gómínà nìkan ni Ekiti nílò báyìí fún ọjọ́ ọ̀la tó dára- Oluwole Oluyede

Ẹ̀gbẹ́ ADC lo le fọwọsowọpọ yanju iṣoro Ekiti bayii- Oluyede

Akọṣẹmọṣẹ oniṣegun oyinbo ni Oluwole Oluyede to n dije dupo gomina Ekiti labẹ asia ẹgbẹ oselu African Democratic Congress.

O sọrọ lori awọn aṣiṣe to ti waye ninu isejọba ipinlẹ Ekiti tẹlé ati ohun to yẹ ni ṣiṣe bayii.

Oluwole Oluyede ti ẹgbẹ ADC tun sọ nipa ọna abayọ si isọrọ awọn eniyan Ekiti lasiko yii.

O menuba awọon nkan to fẹ se lọna to yatọ ni ipinle Ekiti.

O ni ifọwosopọ lo le ko Ekiti yọ ti ẹgbẹ rẹ si duro fun.