Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ mẹ́rin tó fi Rofia ṣòògùn owó ti sùnlọ níbi tí wọ́n ti n jó orí rẹ- Olóri fijilante Abeokuta

Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ mẹ́rin tó fi Rofia ṣòògùn owó ti sùnlọ níbi tí wọ́n ti n jó orí rẹ- Olóri fijilante Abeokuta
Ohun ibanujẹ ni ki majesin o toju Obi rọrun.
Ohun to n panilẹkun ni pe ki awujọ di ibugbe ika to kun fun iṣẹlẹ to n kọnilominu.
BBC Yoruba ti lọ si Adugbo ti awọn ọmọdekunrin mẹrin kan ti fẹ fi orebinrin ọkan lara wọn ṣe oogun owo ni Adatan ni ilu Abeokuta'Orí Facebook ni mo ti kọ́ nípa òògùn owó táà gé orí Sofiat fún ní Abeokuta'

Oríṣun àwòrán, others
Kini awon omokunrin yii n sọ?
Ọkan ninu awọn ọmọkunrin to fi ọmọbinrin kan ṣoogun owo nilu Abeokuta, ti jẹwọ pe ori ayelujara Facebook ni oun ti kọ nipa oogun owo.
Nigba to n ba awọn akọroyin sọrọ ni olu ileeṣẹ ọlọpaa nilu Abeokuta, Balogun Mustaqim to jẹ ẹni ọdun mọkandinlogun sọ pe ọsẹ meji ni awọn fi ṣe igbaradi fun fifi Rofiat Kehinde ṣe oogun owo.
- Ohun tí ó ṣokùnfà ikú Fadlullah Agboluaje, akẹ́kọ̀ọ́ tó kú sí Ukraine ní ọjọ́ kejì tó dé ibẹ̀
- Tí òògùn owó bá wà nínú Ifa ni, n kò bá ti kọ́ ilé ńlá fún ara mi- Babaláwo
- Kìnìún méjì ṣekùpa olùṣọ́gbà ẹranko, wọ́n sì sálọ
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ekiti sàfihàn àwọn òníjàgídíjàgán méjìdínlọ́gọ́rùn ún lónìí ní Ado Ekiti
- Ìdí rèé tí Yahaya Bello fi gbọdọ̀ dá Amotekun sílẹ̀ ní Kogi- Gani Adams
- Wo àwọn ìgbéyàwó tí ayé pariwo wọ́n lọ́dún tó lọ
Oga Olopaa, Abimbola Oyeyemi salaye fun BBC Yoruba pé àwọn ọmọ yìí ń lọ sílé ẹjọ́ láipẹ̀.
Bakan naa lo sọ pe awọn Obi ti kuna nínú Ojúṣe wọn ni irú ohun ìbànújẹ́ báyìí ṣe n pọ̀ síi lasiko yii
- Wo Mẹkáníìkì alápá kan tí ayé ń pariwo pé o mọ ìjánu ọkọ̀ ṣe púpọ̀
- Èmi kò kí ń gba 'Bribe'tàbí mú ọkọ̀ tàbí ọlakadà lẹ́nu iṣẹ́- Olaseni Gbenga Olùdarí ọkọ̀
- Báyìí kọ́ ní wọ́n ṣe bí èmí àti aya mi ṣùgbọ́n a kọ̀ láti tọrọ bárà- Tokotayà tó ni ìpènijà oju
- Kí ló dé tí ọba méjì fi ń dé àdé nílùú Ikere Ekiti?
- Wo Omi-Dájì, odò ìsẹ̀ǹbáyé tó ń fún àgàn lọ́mọ, ṣe ọ̀pọ̀ ìwòsàn tó lágbára
- Akàwégboyè Alákàrà