Lateef Adedimeji ti gbé Adebimpe Oyebade ní ìyawó

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA
Gbajumọ oṣere tiata Yoruba, Lateef Adedimeji ti gbe akégbẹ rẹ nidi iṣẹ tiata, Adebimpoe Oyebade niyawo.
Igbayawo naa waye niluu Ikole Ekiti, ni ipinlẹ Ekiti, nibi ti ọpọ ero peju si.
Ṣaaju ni Lateef ti kọkọ sọ fun BBC Yoruba ninu ifọrọwanilẹnuwo kan pe lootọ ni awọn mejeji yoo ṣe igbeyawo laipẹ.
- Ó ti ṣe díẹ̀ tí mo ti ń gbé pẹ̀lú ìbànújẹ́, ayé ti sú mi - Ibrahim Chatta
- Ìyàwó Timothy Adedoge ké gbàjarè lórí èsì àyẹ̀wò ikú tó pa ọkọ rẹ̀
- Ọkọ mi ti ń sọ tẹ́lẹ̀ pé òun yóò pa ara òun, àmọ́ ẹbí kò ka ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí - Ìyàwó ọkùnrin tó bẹ́ sí odò ọ̀sà
- Ọmọ oṣù mẹ́fà tí ìròyìn sọ pé ọ̀gá ìyá rẹ̀ fi ipá gbà nítorí gbèsè nílùú Eko ti padà kú
- 'Mi ò rí ọkùnrin bá lòpọ̀ fún ọdún kan gbáko lásìkò "lockdown" àmọ́ mo dán ǹkan wò'
- Àjò kò lè dùn títí... Mò ń padà sí oko lẹ́yìn sáà ìjọba mi - Buhari
Ifọrọwanilẹwo naa ni igba akọkọ ti Lateef yoo sọ fun awọn akọrọyin pe lootọ ni awọn mejeji yoo di tọkọ-taya, bo tilẹ jẹ pe awọn ololufẹ wọn ti kọkọ sọrọ nipa igbeyawo naa lori ayelujara ṣaaju.
Lẹyinorẹyin, Lateef gbe Adebimpe niyawo lọjọ kejidinlogun, oṣu kejila, ọdun 2021 yii.
Awọran bi eto igbeyawo naa ṣe lọ ree.

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA

Oríṣun àwòrán, EMIRALTY AFRICA








