Abortion rights march: Ìdí tí ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ènìyàn ló ṣe ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn lórí ẹ̀tọ́ láti ṣẹ́yún

An abortion rights protester outside the US Supreme Court building

Oríṣun àwòrán, Alex Wong

Ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀, àwọn ènìyàn lo wọ́de jákèjádò àwọn ìpínlẹ̀ àádọ́ta láti gbárúkù ti ẹ̀tọ́ ṣíṣẹ́ oyún

Wọ́n pẹ́jọ láti tako òfin tuntun ti wan ṣe ni Texas tí kò fún àwọn obìnrin láànfàní láti ṣẹ́ oyún.

Àwọn olùfẹ̀hònún jákèjádò orílẹ̀-èdè náà ń bẹ̀rù pé, ìjọba ń tẹ ẹ̀tọ́ àwọn lójú mọ́lẹ̀.

Àkọlé fídíò, 'Ìyà Muinat kú nígbà tó ń mu ọmú lọ́wọ́ ni èmí ìyà-ìyá rẹ̀ ń tọ́jú rẹ̀ kí ògiri kíláàsì tó wó pa á'

Ní oṣù díẹ̀ sí àsìkò yìí ni ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ yóò gbọ́ ẹjọ́ tí ó ṣeéṣe kí ó da èja Roe V. Wade tí ó sọ oyún ṣíṣẹ́ dí òfin jákèjádò olrílẹ̀-èdè yìí.

Ní Washinton DC, àwọn olùwọ́de lọ sí ìwájú ilé ẹjọ́ gíga ti wọ́n sì gbé àkọlé bí, ẹ sọ oyún ṣíṣẹ́ di òfin.

Awọn olùwọ́de obìnrin to kóra wọn jọ ti wọ́n n ṣe ìwọ́de láti tako ìwọ́de tó ni ko si ààyè fún ìṣẹ́yún ni Los Angeles lọjọ́ kejì oṣu kẹwa ọdun 2021

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Ìwọ́dé ń wáyé ni Los Angeles, tó fi mọ́ Washington DC

Àwọn olùwọ́de tako ìwọ́de náà ti kaka da ìwọ́de òhun rú sáájú

" Wọ́n n kéde pé, ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọ aláìṣẹ̀ ń bẹ̀ lórí rẹ" Ọkùnrin kan lo ké bẹ́ẹ̀, sùgbọ́n aríwo àti àtẹ́wọ àwọn èrò tó kù ló bo tiẹ mọ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òiwé ìròyìn Washinton Post ṣe sọ.

Ọ̀kan nínú àwọn obìnrin to wà níbẹ̀ ṣàlàyé pé àwọn jáde wá láti gbárúkìu tí ẹ̀tọ́ obìnrin láti yan ǹǹkn ti wọ́n fẹ́.

"Bí o'tílẹ̀ jẹ́ pé, emi gan ko ní ìdí láti kójú irú ìpínú bẹ́ẹ̀, síbẹ̀, àwọn ọ̀pọ̀ obìnrtin mííràn ni irú rl ti dé bá, sìugbọ́n àwọn ìjọba àsti àwọn ọkùnrin kò ni ẹ̀tọ́ láti sọ nǹkan tí obìnrin yóò fi ara rẹ̀ ṣe.

Supporters of reproductive choice take part in a rally in New York Awọn alátìlẹ́yìn, ètò "Reproductive Choice " náà kópa níbẹ̀

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Àwọn tó wà ní ìdí ètò òiwọ́de obìnrin ọlọ́dọọdún lo ṣe àsgbédidé ìwọ́de ìfẹ̀hónú hàn náà.

Àwọn tó ṣe agbátẹrù, ètò ìwọ́de àwọn ob]inrin ọlọ̀dọọdún , Akọ́kọ́ ètò wọn ló mú mílíọnù ènìyàn jáde láti wọ́de ìfẹ̀hónúhàn lẹ́yìn ìbúra wọlé fún ààré Donald Trunp ní ọdún 2017.

Ọ̀pọ̀ àwọn obinrin lo pejọ láti wọde ìfẹ̀hónúhàn lórí pé ẹ̀ya obìntin ná láti ṣẹ́yún tó bá wùú ni Austin, ni Texas lọjọ keji osù kẹwaa 2021

Oríṣun àwòrán, Reuters

Ní ìpińlẹ̀ New York, Gómìnà Kathy Hochul sọ̀rọ̀ nibi ètò ìwọ́de méjì.

" O tí sú mi láti maa jà lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀ta obìnrin láti ṣẹ́yyún. "Òfin tí o ti pari ni lórílẹ̀-èdè yìói. ẹ o sì ni gba ẹ̀ytọ́ náà kúrò ni ọwọ́ wa, kìí ṣe ni àsìkò yìí tàbí láíláí".