Toyin Atoyebi mechanic: Ẹ wo Toyin, ọmọbinrin ọdún 16 tó ń tún ọ̀kadà àti gẹnẹrátọ̀ ṣe ní
Lati kekere ni mo ti n kọṣẹ lọwọ baba mi- Toyin Ganiyu Atoyebi
Akọṣẹmọṣẹ mọkaniiki to n tun ọkada ati generato ṣe ni baba Toyin nigba aye rẹ ki ọlọjọ to de.
Toyin Ganiyu Atoyebi to n lọ sile iwe Bishop Smith ni Ilọrin ni ipinlẹ Kwara ni guusu iwọ oorun Naijiria ṣalaye ohun ti oju rẹ ri to fun BBC.
- Akọ̀wé-owó wọ gàù ní iléẹjọ́ lórí ẹ̀sùn pé ó jí N500,000 lọ́wọ́ ọ̀gá rẹ̀
- Ìdùnú subú layọ̀ nípìnlẹ̀ Ọyọ́, àwọn tó dé láti Lebanon sọ ọmọ wọn ní Seyi
- Daniel ń bọ̀ wá wò mí nítori mo ṣàìsàn ló dàwátì- Baba Daniel
- Ilé iṣẹ́ ọmọogun òfurufú sọ orúkọTolulope Arotiba di málegbàgbé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà
- Ẹgbẹ́ NULGE Oyo dìbò yan olóyè ẹgbẹ́ tuntun èyí tó tako àṣẹ iléẹjọ́
Awọn onibara Toyin naa ba BBC sọrọ wọn ni ọmọluwabi ni to tun ni itẹriba lẹnu iṣẹ ọwọ rẹ.
Abimbọla Oluwafẹranmi to jẹ Iya baba Toyin naa sọrọ ilẹ kun lori ipa ribiribi ti Toyin n ko lati pese fun ẹbi rẹ lati igba ti baba rẹ ti ku.
- Lawuyi Ogunniran, àgbà ọ̀jẹ̀ òǹkọ̀wé Eégún Aláré dágbére fáyé!
- Orílẹ̀èdè Amẹrika ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wo wọlé-wọ̀de Atiku, àwọn ìyàwo rẹ̀ lórí owó tí wọ́n kó lọ sí òkèèrè
- Obaseki ní kí Ize-Iyamu wá bá òun ṣiṣẹ́ lẹ́yìn tó lù ú lálùbami nínù ìdìbò sípò gómìnà Edo
- Ọ̀gá iléeṣẹ́ gbé £10 mílíọ̀nù ẹ̀bùn owó fún òṣìṣẹ́, èyí lohun tó pawọ́n pọ̀
- Ìjọba Katsina ní kí àwọn iléèwé wà ṣì ní títìpa nítorí arùn Coronavirus
Toyin gba awọn ọdọbinrin bii tirẹ nimọran pe ki wọn ni afojusun lori iṣẹ ti wọn ba n ṣe ati ninu iwe ti wọn n ka ki wọn le sinmi lọjọ ọla.

