Risikat Ilorin blue eyes woman: Inú èmí àti Òbí mi dùn nígbà ti Risi bí ọmọ olójú búlù àmọ́ ... - Wasiu
Mo fẹ ki Risikat pada sile ọdọ mi ni- Wasiu ọkọ Risikat
"Mo fi Àlìkùrání búra pé mò ń tọ́jú Risikat àti àwọn ọmọ mi- Bàbá àwọn ọmọ olójú búlúù

Wasiu to jẹ ọkọ Risikat oloju buluu ba BBC Yoruba sọrọ ni kikun lori ohun to ṣẹlẹ ki Risikat to ko lọ ati lẹyin to kuro nile rẹ.
O ni o ba oun ninu jẹ lati gbọ irọ ti wọn n pa mọ oun pe oun le Risikat nile nitoripe o loju buluu.

O sọrọ nipa awọn owo ti ohun ti na lori oju iyawo rẹ ati awọn ọmọ rẹ mejeeji.
Koda, O fi Alkurani bura pe oun n ṣe ẹtọ to yẹ lori wọn.
- Àwọ̀ ojú pọ̀ bíi àwọ̀ òṣùmàrè, àmọ́ ojú búlúù Risikat kò nílò àtúnṣe- Dókítà Feyi
- Mínísítà fún ọ̀dọ́ àti eré ìdárayá tí fi ẹ̀bùn owó ránṣẹ́ si ìyá Kausara, ó tún jẹ́jẹ̀ẹ́ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ f'áwọn ọmọ rẹ̀
- Ogundipe gbé fásitì Unilag ló sí iléẹjọ́ nítórí wọn yọ́ ní ipò VC
- Ilé ayé mi ti d'ojú bolẹ̀ pẹ̀lú ikú àfẹ́sọ́nà mi- àfẹ́sọ́nà Immaculate Okochu
- Àgbo Covid-19 Madagascar kò ṣiṣẹ́, àwọn ènìyàn tí bẹ̀rẹ̀ sí ní kú níbẹ̀

Risikat naa fidiẹ mulẹ pe nitootọ ni Wasiu ko le oun nile ṣugbọn iwa rẹ fihan pe ki oun ba ẹsẹ oun sọrọ nigba naa.
O fi ẹsun kan awọn Obi Wasiu pe wọn maa n sọrọ nitori awọ buluu oju oun ati tọmọ ṣugbọn Wasiu ni irọ ni pe inu Obi oun dun si awọ oju rọ.

Ile Olọmọyọyọ to jẹ agboole wọn ni BBC Yoruba lọ lati rii wọn ki a si mu oju aje kọ onisọ lati mọ okodoro ohun to ṣẹlẹ gangan
Iya ati Baba Risikat naa sọ iha ti wọn kọ si ohun to ṣẹlẹ.
Wasiu Jimoh ni oun diidi gbadura fun Risikat lati bi ọmọ oloju buluu ni ki awọn to bimọ ati pe oju yii ni Risikat fi n wu oun.
O ni oun fẹ ki Risikat ko pada wa sile ṣugbọn kii ṣe nitori owo ti o ti pa lọwọ awọn eeyan rara.

Oríṣun àwòrán, Mofe Bamuyiwa
- Ìbejì wù mí láti kékeré ṣùgbọ́n mí ò mọ̀ pé ìbẹfà lorí kọ mọ́ mi- Ifeoma Ìyá Ìbẹfà
- Ṣé ìrànwọ̀ ni Kamala, ìgbákejì tí Biden yàn yóò jẹ́ fún un tàbí ìpalára?
- "A ti ń sin òkú méjì sínú ibójì kan náà nítorí ọ̀wọ́ngógó ibojì ìsìnkú"
- Wo díẹ̀ nípa ohun tí Walter Carrington gbé ṣe nígbà ayé rẹ̀
- Ẹgbẹgbẹ̀rún ọmọ Nàìjíríà ní yóò má a kú lójoojúmọ́ tí wọn bá gbà wọ́n láàyè láti gbébọn dání- Amofin
- Ilé ẹjọ́ ju ọmọ ìjọ tó fi ìpá bá ọmọ pásítọ̀ rẹ̀ sùn ní ìpínlẹ̀ Ondo sí ẹ̀wọ̀n gbére
