Christmas: Ẹni ti ọdun ba ti bá láyé yẹ kó dúpẹ́
Odun keresimesi wọle de wẹre
Ẹni ti ọdun ba ti ba laye ni ko ṣọpẹ ni awọn agba ilẹ Yoruba maa n wi.
BBC Yoruba ki gbogbo ọmọ lẹyin Kristi ku oriire ọdun Keresi ti o wọle de wẹrẹ yii pe, pataki ìbí Jesu a wa si imuṣẹ lori koowa.
Oriṣiriṣi orin ni ede oniruuru ni awọn eeyan fi maa n kọ orin Keresimesi kaakiri agbaye.
BBC Yoruba jade ni ki awọn eniyan kọ orin keresi to wu wọn,
E wo bi ohun awọn eeyan ṣe n ja geere ti wọn n ṣajọyọ ìbí Jesu!
Takọtabo lo n yọ ayọ Olugbala ti a bi fun wa nitori alaafia awa ẹda
- Òtútù àmújù àti ìjí líle kọlu Amẹrika, èèyàn méjìlá kú, 1.5m èèyàn kò rí ìna ìjọba lò
- Ilé ẹjọ́ kéde ọmọ Sanni Abacha gẹ́gẹ́ bíi ojúlówó olùdíje gómìnà nínú ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nípìnlẹ̀ Kano
- Ṣé ẹ ti ra fìlà ọdún? Dárúkọ ọjà Kérésí kan tí ẹ̀yin ti rà
- Àhámọ́ ọlọ́pàá ni Adeyẹmi, ọmọ gbajúmọ̀ Ọba yóó ti ṣọdún Kérésìmesì
- Wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré Yorùbá tó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà míì àti orílẹ̀èdè míì
- Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa adẹ́rínpòṣónú, Peteru tó jáde láyé
- Ibi tí o bá dágbére fún ẹbí àti ará ní kí wọ́n ti ba ọ lásìkò ọdún Kérésì yìí- Akọ́ṣẹ́mọ́ṣẹ́ Bolarinwa