Tacha: Wọ́n lé e dànù nínú ìdíje BBNaija tó ń lọ lọ́wọ́ tori jàgídíjàgan

Aworan Tacha

Oríṣun àwòrán, BB Naija

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Oye to kan ara iwo Cindy lori eto BBN ti kan ara Ẹdẹ Tacha pẹlu bi wọn ti ṣe fọwọ osi juwe ile fun kuro ninu ile ẹlẹgbọn.

Laarin awọn to n fi ọkan ba eto naa bọ,pupọ a ma sọ pe dundun Tacha ti n lata pupọ ju ti wọn si ni o ti yẹ ki wọn ti le kuro nile naa.

Ọpọ igba ni wọn ti kilọ fun Tacha lori eto naa amọ lile ti wọn le yi rọmọ wiwu iwa jagidijagan lori eto naa.

Kete ti ikede lu sita pe wọn ti le kuro loju opo Twitter gbana jẹ.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Ni bayi,wọn ti fun Mercy ti ohun ati Tacha jijọ bara wn ja ni ikilọ ẹlẹẹkeeji.

Ti ohun naa ba file ṣe aṣemaṣe miran bayi,o ṣeeṣe ki ohun naa di ero ile.

Ki lo ṣẹlẹ saaju?

Wọn ti le Cindy Okafor, to jẹ ọkan lara awọn olukopa ninu idije BBNaija 2019 to n lọ lọwọ pada sile.

Cindy ni wọn le lai ro tẹlẹ nigbati adari eto naa, Ebuka Obi-Uchendu, ṣadede wọle tọ awọn olukopa lori eto naa lowurọ oni.

Bi wọn ṣe ni ni ki Cindy lọ rọku nile yii jẹ iyalẹnu fun ọpọlọpọ ninu awọn olukopa idije naa, nitori ọjọ Aiku nikan ni wọn wọn ma n le awọn eeyan.

Lana ode yii ni onigbọwọ eto ọhun kede loju opop Twitter rẹ pe, oṣeeṣe ki wọn juwe ile fun ọkan lara awọn to wa ni ile BBNaija ọhun.

Leyi to mu ki ọpọlọpọ awọn ololufe eto naa joko ti ẹrọ amohunmaworan wọn, lati mọ ẹni ti yoo kuro ninu ile naa.

Sugbọn laarọ yii ni BBNaiji gbọna mii yọ, ti wọn si sọ fun Cindy pe, ile ya.

Awọn to ṣeṣe ki wọn kuro ninu ile naa laipẹ ni, Tacha, Elozonam ati Ike.