Freedom Park: Ẹ̀wọ̀n tí àwọn òyìnbò lọ fún ọdun 100 ní Naijiria rèé tí ọ̀pọ̀ ẹ̀mí lọ̀
Ni ọdun 1872 ni awọn oyinbo kọkọ kọ ọgba ẹwọn ni orilẹede Naijiria ti o si wa fun ọgọrun ọdun ki wọn to wo palẹ ni ọdun 1972.
Awọn oyinbo ọhun ni wọn kọ ẹwọn naa lẹyin ti wọn gba ilu Eko lọwọ Dosunmu pẹlu adehun ni ọdun 1861.
Lara awọn ohun to jẹ iyalẹnu ni pe ojo kii rọ lasiko ti wọn ba n ṣe ayẹyẹ ninu ọgba Freedom Park naa.
- Wọ́n ti ń bèrè lọ́wọ́ abúrò ọkọ mi pé èlò ni wọ́n fẹ́ gbà, ẹ ṣàánú wa o! - Ìyàwó Timothy tó kú sí Hilton Hotel Osun figbe ta
- Wọ́n lù mí bíi ẹní máa kú, wọ́n ya aṣọ mọ́ mi lọ́rùn nílé Princess kí n tó dé àgọ́ ọlọ́pàá - Baba Ijesha
- Èsì ìjọba Naijiria rèé sí Baba Itunu Babalola tó ń béèrè fún òkú ọmọ rẹ̀ àti irú ikú tó pa á
- Wo bí ọkọ̀ tó gbé bẹntiróò ṣe gbiná n'Ibadan, ọkọ̀ méjì jóná ráùráú
- Gbas-gbos ti ń wáyé ṣáájú ìdìbò sí ipò gómìnà Osun, kí ló ń ṣẹlẹ̀ láàrín Aregbesola, Oyetola?
- Àwọn alamí ìjọba kan ti wà láàrín àwa ajìjàgbara Yoruba Nation tó ń bínú pé Sunday Igboho ti ga ju àwọn lọ - Akintoye
- Buhari ti sọ̀rọ̀ sókè lórí àbájáde ìwádìí EndSARS, ilẹ̀ Amẹ́ríkà sì ti fun lésì
- Ẹkún gbígbóná lójú abiyamọ! bàbá Itunu Babalola barajẹ́ lórí ọmọ rẹ̀ tó kú sí ẹ̀wọ̀n ní Côte d'Ivoire
- Lẹ́yìn Titi Masha, Kwam 1 gbé ìyàwó tuntun, Emmanuella Ropo l'Abeokuta, bó ṣe lọ rèé
Igbagbọ wọn si ni pe awọn oku ati abami ẹda ti wọn pa laarin ọgọrun un ọdun naa lo wa si ibẹ lati wa gba isinmi.
Ẹkunrẹrẹ ohun iyalẹnu miran wa ninu fidio yii...


