Stingy Men Association: Ojú òpó Twitter ń ṣọkutu wọ̀wọ̀ pẹ̀lú ọ̀rọ̀ àwọn ọkùnrin ahun

Ojú òpó Twitter ń ṣọkutu wọ̀wọ̀ pẹ̀lú ọ̀rọ̀ àwọn ọkùnrin ahun

Oríṣun àwòrán, Twitter

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Njẹ ẹyin mọ ẹgbẹ tuntun tawọn eeyan n sọrọ rẹ bayii lori ayelujara ni Naijiria bayii?Ẹ maa laagun jinna, ẹgbẹ awọn ọkunrin to lahun s'awọn ọrẹbinrin wọn ni ti wọn n pe ni Stingy Men Association of Nigeria.O gbẹnutan o! Oríṣiiriṣii àpẹẹrẹ irufẹ awọn ọkunrin bẹẹ lawọn eeyan n fi lede loju opo Twitter.

@nwoguprestige fi fọto ọkunrin kan ti wọn lo fi ẹgbẹrun meji naira(#2000) ranṣẹ si ọmọbinrin to ṣẹṣẹ pade laarin ọjọ mẹta lori Facebook.Idajọ ẹgbẹ awọn ọkunrin to lahun ni pe ki ọkunrin naa lọ fi ẹwọn aadọta ọdun jura.@kingfreezy ni tirẹ fi aworan ọkunrin kan ti wọn fẹsun kan pe o fi ẹgbẹrun mẹwaa naira(10,000) ranṣẹ si ọrẹbinrin rẹ gẹgẹ bi owo ọkọ.Ẹgbẹ awọn ọkunrin to lahun koro oju si igbesẹ rẹ.Orin apilẹkọ ẹgbẹ awọn ọkunrin alahun ti @coolehizy1 fi lede loju opo Twitter rẹ.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

O ṣalaye ninu ọrọ to fi si oju opo Twitter rẹ pe orin naa niiṣe pẹlu ilanilọyẹ lori ẹgbẹ awọn ọkunrin naa.@Mayor_fx sọ ni tirẹ pe bi wọn ti gbọn nile ọkọ naa ni wọn gbọn nile ale.

Gbajugba olori Don Jazzy naa wa lara awọn to kọkọ farahan pe ọmọ ẹgbẹ ni òun

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

O ṣalaye pẹlu aworan meji pe bi ọkunrin ba kọ lati fun ọrẹbinrin rẹ lowo, ọrẹbinrin naa ko ni fẹyin le lẹ.Ẹwẹ, ọrọ ati gba kaadi idanimọ ẹgbẹ awọn ọkunrin ahun lo jẹ awọn kan logun ni tiwọn.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Kí ló ń pa ẹbí Orisabunmi lọkọ́ọ̀kàn, àkúfà ni àbí àmúwá Ọlọ́run?

Oríṣun àwòrán, Tommyvicceti/twitter

Títí di àsìkò yìí kò sí ẹni tó yé ìdí ti àwọn okùnrin fi fáríga lórí pé àwọn kò ni fún obìnrin lówó mọ.