Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Tuntun ti de lagbo eto ẹkọ ni Naijiria
Ewo laa tun ri gbọ o
Minisita eto ẹkọ lo ṣe agbekalẹ aba ìlànà ètò ẹ̀kọ́ tuntun eyi tí yòó da ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama pọ̀ ní Nàìjíríà
ọdun meloo wa lawọn akẹkọọ yoo maa lo nile ẹkọ alakọbẹrẹ ati girama bayii?
Lọ sori ikanni BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ipinlẹ Ibadan ati Ife-Ijesha wa lara ipinlẹ mọkanlelọgbọn ti ile aṣoju-ṣofin l'Abuja n dabaa fun ìjọba apapọ lati da silẹ
Mẹfa ni ipinlẹ tuntun ti yoo wa lati ilẹ Yoruba ninu gbogbo awọn ipinlẹ yii
Yatọ si Ibadan ati Ife-Ijesha, awọn ipinlẹ tuntun mii wo ni yoo jade lati ilẹ Yoruba?
Alaye wa loju opo BBC.Com/Yoruba
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ọwọ ọlọpaa ti tẹ ọkan lara awọn afurasi ọdaran to ṣeku pa eeyan mẹẹẹdogun
ti wọn si dana sun ọpọ ile nipinlẹ l'Ebonyi, laipẹ yii,
ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ebony sọ pe awọn agbofinro mu afurasi naa pẹlu iranlọwọ awọn araalu.
Gomina Francis Nwifuru ti ni gbogbo awọn to wa nidi iṣẹlẹ ọhun ni yoo foju wina ofin
















