Mohbad gba àmì ẹ̀yẹ Headies, wo bí àmì ẹ̀yẹ náà ṣe lọ lọ́dún yìí

Aworan Mohbad ati idanimọ Headies.

Oríṣun àwòrán, headies/x

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 6

Ami ẹyẹ fun wọn olorin, Headies, ẹlẹkẹtadinlogun iru ẹ waye ni ilu Eko lorilẹede Naijiria.

Headies jẹ ọkan gboogi lara awọn ami ẹyẹ fun olorin lorilẹede Naijiria.

Lara awọn ilumọọka olorin to da ilu bolẹ nibi ayẹyẹ ami ẹyẹ naa ni Shallipoppi, Chike, Juma Jux, Yemi Alade ati Qing Madi.

Igba akọkọ niyi laarin ọdun meji ti ami ẹyẹ yii yoo waye lorilẹede Naijiria lẹyin ti wọn gbe e lọ si oke okun, lorilẹede Amẹrika fun ọdun meji.

Ami ẹyẹ naa fun ọdun 2022 ati 2023 waye ni ilu Atlanta, Georgia lorilẹede Amẹrika, idi sin iyi ti wọn fi pe akori ti ọdun yii ni "Pipada si ipilẹ".

Ọga agba ileeṣẹ to n gbe ami ẹyẹ naa jade, Ayọ Animashaun ni ayẹ naa yoo waye fun fun igba meji lọdun yii lati to ami ẹyẹ naa pada si ẹsẹẹsẹ to yẹ.

Ipele mẹta lo wa fun ami ẹyẹ lọdun yii.

Awọn akọrin to si gba idanimọ to pọ julọ ni Ayra Starr ati Odumodublvck. Ipele mẹjọ ọtọtọ lorukọ wọn ti jade

Bakannaa ni Tems ati Asake wey jade ni ọna mẹfa ọtọọtọ, bẹẹni orukọ Shallipopi jade ni ipele marun un.

Aworan Tems

Oríṣun àwòrán, Headies/x

Iwe orukọ awọn olorin to wọ iwe ami ẹyẹ Headies tọdun 2025

Skip podcast promotion and continue reading
Èyí ni ìkànnì Whatsapp wa

Àjáàbalẹ̀ ìròyìn BBC News Yorùbá lórí WhatsApp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa nibì

End of podcast promotion

Ọjẹ wẹwẹ akọrin fun ọdun 2025

ZERRY DL (Olubori)

TAVES

KAESTYLE

LLONA

Akasilẹ orin to pegede julọ lọdun 2025 (BEST RECORDING OF THE YEAR)

TEMS – BURNING - (olubori)

DIFFERENT PATTERN - SEYI VIBEZ

HIGHER - BURNA BOY

LAST HEARTBREAK SONG - AYRA STARR & GIVEON

BILLIONS - SARZ FEATURING LOJAY

Akọsilẹ orin to pegede julọ (SONGWRITER OF THE YEAR)

SIMISOLA KOSOKO - STRANGER (SIMI)

CHIMAMANDA PEARL CHUKWUMA - VISION (QING MADI) - (olubori)

MICHAEL AJUMA ATTAH - CAN'T BREATHE (LLONA)

EMOSEH KHAMOFU - FAMILY MEETING (BLOODY CIVILIAN)

FUAYEFIKA MAXWELL - STAGES OF LIFE (WIZARD CHAN)

Orin R&B SINGLE to pegede julọ

QING MADI – VISION

JOHNNY DRILLE - FOR YOU

SIMI – STRANGER

TEMS – BURNING

AYRA STARR - LAST HEARTBREAK SONG FT. GIVEON

Olotu iṣẹ orin to pegede julọ (PRODUCER OF THE YEAR)

SARZ – HAPPINESS

LONDON – OZEBA - (olubori)

MAGICSTICKS – BASQUIAT

REMA/PRODUCER X/CUBEATZ/DEATZ/KLIMPERBOY – HEHEHE

DIBS - DIFFERENT PATTERN

Orin RAP SINGLE to pegede julọ

CAST FEAT ODUMODUBLVCK – SHALLIPOPI

BLOOD ON THE DANCE FLOOR FEAT BLOODY CIVILIAN & WALE – ODUMODUBLVCK

HALLELUJAH - LADIPOE, ROZZZ & MORRELO

CANADA - MAGNITO

IJE NWOKE - JERIQ

Ohun orin to pegede julọ lobinrin (BEST VOCAL PERFORMANCE (FEMALE))

AYRA STARR - LAST HEARTBREAK SONG

NINIOLA - LEVEL

SIMI – STRANGER

LIYA – I'M DONE - (Olubori)

TOMORROW - YEMI ALADE

Ohun orin to pegede julọ lọkunrin (BEST VOCAL PERFORMANCE (MALE))

LOJAY – BILLIONS - (Olubori)

OMAH LAY - MOVING

ANENDLESSOCEAN – GRATITUDE

JOHNNY DRILLE - FOR YOU

TIMI DAKOLO - KE NA KE SO

Fidio orin to pegede julọ (MUSIC VIDEO OF THE YEAR)

CHARM - REMA (REMA X PERLIKS X FOLARIN OLUDARE)

METAVERSE - OLAMIDE (JYDE AJALA)

LIKE ICE SPICE - BLAQBONEZ (PERLIKS & EMEKA SHINE SHINE)

OJAPIANO - KCEE (MATTMAX)

EGWU - CHIKE & MOHBAD (DIRECTOR PINK) - (Olubori)

SHOWA - KIZZ DANIEL (TG OMORI)

NA MONEY – DAVIDO FT. CAVEMEN, ANGELIQUE KIDJO (DAMMY TWITCH)

Orin ajumọkọ to pegede julọ (BEST COLLABORATION)

EMOTIONS - TIWA SAVAGE FEAT. ASA

BLOOD ON THE DANCE FLOOR - ODUMODUBLVCK, BLOODY CIVILIAN, AND WALE

CAST - SHALLIPOPI FT ODUMODUBLVCK

EGWU - CHIKE AND MOHBAD

OLE - QING MADI AND BNXN

TWE TWE REMIX – KIZZ DANIEL AND DAVIDO

IDK – WIZKID FT. ZLATAN

Akọrin Hip-Hop to pegede julọ (BEST STREET-HOP ARTISTE)

SEYI VIBEZ – "DIFFERENT PATTERNS

AYO MAFF – DEALER (FT. FIREBOY DML)

SHALLIPOPI – CAST (FT. ODUMODUBLVCK)

ZHUS JDO – JOHNBULL

MOHBAD – ASK ABOUT ME - (Olubori)

Orin Afrobeats to pegede julọ (AFROBEATS SINGLE OF THE YEAR)

BIG BIG THINGS - YOUNG JONN FT. KIZZ DANIEL AND SEYI VIBEZ

TWE TWE REMIX - KIZZ DANIEL

EGWU FEAT. MOHBAD – CHIKE

REMEMBER – ASAKE

OGECHI REMIX - HYCE, BOYPEE, AND BROWN JOEL FT. DAVIDO

BIG BALLER – FLAVOR - (Olubori)

Akọsilẹ orin to pegede julọ (LYRICIST ON THE ROLL)

MOGADISHU - A-Q

CHOCOLATE CITY CYPHER - M.I ABAGA

CHOCOLATE CITY CYPHER – BLAQBONEZ

HALLELUJAH – LADIPOE

EFELEME - ALPHA OJINI

Orin to ni imisi julọ (BEST INSPIRATIONAL SINGLE)

GRATITUDE – ANENDLESSOCEAN

WORTHY OF MY PRAISE - DUNSIN OYEKAN FT. LAWRENCE OYOR

GOOD GOD 2 - LIMOBLAZE FT. NAOMI RAINE

PARTICULARLY - GAISE BABA FT. TOPE ALABI

YOU DO THIS ONE - MERCY CHINWO - (Olubori)

Ohun ti awọn oluworan yan laayo julọ (HEADIES' VIEWERS' CHOICE)

BIG BIG THINGS FT. KIZZ DANIEL AND SEYI VIBEZ - YOUNG JONN

OGECHI REMIX FT. DAVIDO - HYCE, BOYPEE, AND BROWN JOEL

EGWU - CHIKE & MOHBAD - (Olubori)

SHOWA - KIZZ DANIEL

DIFFERENT PATTERN - SEYI VIBEZ

OZEBA – REMA

LOVE ME JEJE – TEMS

CAST FT. ODUMODUBLVCK – SHALLIPOPI

DEALER FT. FIREBOY DML - AYO MAFF

BIG BALLER - FLAVOUR

Akọrin to pegede julọ ni ẹkun iwọ oorun Afirika (BEST WEST AFRICAN ARTISTE OF THE YEAR)

BLACK SHERIF (GHANA)

KING PROMISE (GHANA)

HIMRA (IVORY COAST) - (Olubori)

JOSEY (IVORY COAST)

TOOFAN (TOGO)

Akọrin to pegede julọ ni ẹkun ila oorun Afirika (BEST EAST AFRICAN ARTISTE OF THE YEAR)

BIEN (KENYA)

DIAMOND PLATNUMZ (TANZANIA)

JUMA JUX (TANZANIA) - (Olubori)

BRUCE MELODIE (RWANDA)

AZAWI (UGANDA)

Akọrin to pegede julọ ni ẹkun ariwa Afirika (BEST NORTH AFRICAN ARTISTE OF THE YEAR)

MOHAMED RAMADAN (EGYPT)

ELGRANDE TOTO (MOROCCO)

SOOLKING (ALGERIA) - (Olubori)

BALTI (TUNISIA)

ABU (EYGPT)

Akọrin to pegede julọ ni ẹkun gusu Afirika (BEST SOUTH AFRICAN ARTISTE OF THE YEAR)

TITOM (SOUTH AFRICA) - (Olubori)

YUPPE (SOUTH AFRICA)

TYLA (SOUTH AFRICA)

KELLY KAY (MALAWI)

PLUTONIO (MOZAMBIQUE)

ZEE NXUMALO (SOUTH AFRICA)

Akọrin to pegede julọ ni ẹkun aringbungbun Afirika (BEST CENTRAL AFRICAN ARTISTE OF THE YEAR)

INNOSS'B (DRC)

GAZ MAWETE (DRC)

EMMA'A (GABON)

EBOLOKO (GABON)

SINGUILA. (CENTRAL AFRICAN REPUBLIC)

KOCEE (CAMEROUN)

Akọrin okeokun to pegede julọ (INTERNATIONAL ARTISTE OF THE YEAR)

WALE - BLOOD ON THE DANCE FLOOR (ODUMODUBLVCK)

SKEPTA - TONY MONTANA (FT. PORTABLE)

CHRIS BROWN - HMMM (FT. DAVIDO)

TRAVIS SCOTT - ACTIVE (ASAKE) - (Olubori)

CHLOE BAILEY - VISION REMIX (QING MADI)

Awo orin RAP to pegede julọ BEST RAP ALBUM

SIDEH KAI – ILLBLISS

EZIOKWU – ODUMODUBLVCK

ALAYE TOH SE GOGO VOL. 1 – REMINISCE

FAMILY TIME – ERIGGA - (Olubori)

SHINY OBJECT SYNDROME – MODENINE

Orin inu sinima to pegede julọ (SOUNDTRACK OF THE YEAR)

ELEDUMARE - TELEDALESE (ANIKULAPO: RISE OF THE SPECTRE)

LOSE TO GAIN - KALINE (BREATH OF LIFE)

KILL BORO - NATIVE FILMWORKS & WIZARD CHAN (KILL BORO)

ORISA - BERIOLA (ORISA)

EMOTIONS - TIWA SAVAGE & ASA (WATER AND GARRI)

TRIBE CALLED JUDAH SOUNDTRACK - TCJ & ABBEY WONDER (A TRIBE CALLED JUDAH) - (Olubori)

Irawọ orin tuntun (NEXT RATED)

QING MADI

SHALLIPOPI

ODUMODUBLVCK - (Olubori)

Awo orin Afrobeat to pegede julọ (AFROBEATS ALBUM OF THE YEAR)

STUBBORN – VICTONY

WORK OF ART – ASAKE

THE YEAR I TURNED 21 - AYRA STARR

HEIS – REMA - (Olubori)

JIGGY FOREVER - YOUNG JONN

Akọrin to danilaraya julọ loju agbo (BEST PERFORMER (LIVE))

REMA - RAVAGE UPRISING: REMA LIVE FROM THE O2, LONDON

OMAH LAY - LIVE AT L'OLYMPIA PARIS

FLAVOUR – CELEBRATING YOU 2023

WIZARD CHAN - LIVE IN CONCERT PORT HARCOURT

BURNA BOY - AFRICAN GIANT LIVE FROM LONDON - (Olubori)

FEMI KUTI & THE POSITIVE FORCE - NUITS DE FOURVIÈRE (ARTE CONCERT)

Ami ẹyẹ pataki (SPECIAL RECOGNITION)

KINGSLEY CHINWEIKE OKONKWO a.k.a KCEE

Ami ẹyẹ fun akọrin igbalode (DIGITAL ARTISTE OF THE YEAR)

AYRA STARR

REMA

SHALLIPOPI

TEMS

DAVIDO - (Olubori)

KIZZ DANIEL

ASAKE

Orin to pegede julọ (SONG OF THE YEAR)

SHOWA - KIZZ DANIEL

COMMAS - AYRA STARR

EGWU - CHIKE AND MOHBAD

LONELY AT THE TOP – ASAKE - (olubori)

OZEBA – REMA

BIG BALLER - FLAVOUR

Awo orin to pegede lọdun (ALBUM OF THE YEAR)

BORN IN THE WILD – TEMS

HEIS – REMA

THE YEAR I TURNED 21 - AYRA STARR

STUBBORN – VICTONY

WORK OF ART - ASAKE

Olorin to pegede julọ (ARTISTE OF THE YEAR)

DAVIDO

AYRA STARR

ASAKE

REMA

TEMS

BURNA BOY