Ọdún 2025 yìí, a ò níì kábàámọ̀ - Ẹ gbọ́ ìwúre ọdún láti ẹnu Ọba Ògbóni Ìgbà Ìwásẹ̀

Àkọlé fídíò, 'Gbogbo nnkan tá a lé tọ́wọ́ wa kò tó ò ní 2024, láo rí ní 2025'
Ọdún 2025 yìí, a ò níì kábàámọ̀ - Ẹ gbọ́ ìwúre ọdún láti ẹnu Ọba Ògbóni Ìgbà Ìwásẹ̀

"Gbogbo nnkan ti a le ni 2024, ti ọwọ wa ko to o, eledumare maa jẹ ki ọwọ wa to ni 2025."

Eyi ni diẹ lara awọn iwure ti Oba Adeyinka Sangolade Arifanlajogun, to jẹ Ọba Aarẹ Ogboni Iwasẹ l'agbaye, wu fun gbogbo ọmọ Naijiria pẹlu bi wọn sẹ wọ inu ọdun tuntun 2025.

Ninu iwure naa lo ti gbadura pe ọdun 2025 yii, a ko nii kabamọ.

Ọba Arifanlajogun tun wure fun orilẹ-ede Naijiria ati ilẹ Yoruba pe, ko nii daru.