Ẹ wá gbọ́ àdúrà ọdún lẹ́nu Sheikh Habeeb Lagbaji
Ẹ wá gbọ́ àdúrà ọdún lẹ́nu Sheikh Habeeb Lagbaji
Àdúrà gbogbo èèyàn náà ni pé kí a máa ṣe ọdún mọ́dún. A dúpẹ́ fún Ọlọ́run tó mú ojú wa rí ọdún 2025.
Kò sí ohun tó dára láti fi bẹ̀rẹ̀ ọdún bíkòṣe ìwúre.
Èyí ló mú kàn sì Alfa àgbà, Sheikh Habeeb Lagbaji láti fún wa ní àdúrà ọdún ní ìlànà ẹ̀sìn Islam.
Sheikh Habeeb Lagbaji ní ẹni tọrẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àánú àti oore lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ọdún 2025.
Ẹ gbọ́ àwọn ìwúre Sheikh Lagbaji nínú fídíò òkè yìí.



