'Bí ẹ ṣé ń wọ ọdun tuntun yìí, ọ̀nà tuntun ṣí fún-un yín'

Àkọlé fídíò, Àdúrà ọdún
'Bí ẹ ṣé ń wọ ọdun tuntun yìí, ọ̀nà tuntun ṣí fún-un yín'

"Bí ẹ ṣé ń wọ ọdun tuntun yìí, ọ̀nà tuntun ṣí fún-un yín.

"Bí ẹ ó ti wọ ọdún tuntun yìí, ọ̀nà tun kó là fún-un yín"

Èyí ni àwọn àgbà ìyanu àdúrà tó ń bọ́ lẹ́nu Wòlíì Hezekiah Oladeji, Ajíhìnrere Àgbà, ti ìjọ Christ Apostolic Church, CAC fún ọdún tuntun.

Wòlíì Hezekiah gbàdúrà pé gbogbo ìdè àti ìjàmbá kò ní ṣẹlẹ̀ sí ẹnikẹ́ni nínu ọdún tuntun tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ wọnú rẹ̀ yìí.

Bákan náà ló gbàdúrà kí ìṣẹ̀lẹ̀ ibi kankan má ṣẹlẹ̀ sí orílẹ̀ Nàìjíríà àtàwọn èèyàn inú rẹ̀ lápapọ̀.