Wo àwọn àwòrán mánigbàgbé nipa ìgbé ayé Gómìnà Rotimi Akeredolu tó jade láyé

Aworan Rotimi Akeredolu pẹlu iyawo rẹ Betty

Oríṣun àwòrán, Arakunrin Akeredolu

Ni owurọ Ọjọru ni iroyin iku gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu SAN, jade si igboro agbaye.

Eyi ni awọn aworan nipa diẹ lara igbesi aye rẹ.

Akeredolu ati iyawo rẹ Betty ni igba ọdọ wọn.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu ati iyawo rẹ Betty ni igba ọdọ wọn.
Akeredolu lo lewaju awọn gomina to ja fitafita fun idasilẹ ikọ Amọtẹkun lati dẹkun gulegule awọn ọdaran daranadaran lẹkun iwọ oorun gusu Naijiria.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu lo lewaju awọn gomina to ja fitafita fun idasilẹ ikọ Amọtẹkun lati dẹkun gulegule awọn ọdaran daranadaran lẹkun iwọ oorun gusu Naijiria.

Akeredolu ati iyawo rẹ Betty lasiko ajọyọ igbeyawo wọn.

Oríṣun àwòrán, thenigerialawyer.com

Àkọlé àwòrán, Akeredolu ati iyawo rẹ Betty lasiko ajọyọ igbeyawo wọn.
Akeredolu nibi eto isinku awọn olujọsin ijọ Aguda St Francis Catholic Church ti awọn agbebọn kan ṣekupa ni ilu Ọwọ ni oṣu kẹfa ọdun 2022.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu nibi eto isinku awọn olujọsin ijọ Aguda St Francis Catholic Church ti awọn agbebọn kan ṣekupa ni ilu Ọwọ ni oṣu kẹfa ọdun 2022.

Akeredolu ko aarun COVID-19 lọdun 2020.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu ko aarun COVID-19 lọdun 2020.
Akeredolu nigba to n dibo lasiko idibo apapọ Nigeria lọdun 2023.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu nigba to n dibo lasiko idibo apapọ Nigeria lọdun 2023.
Akeredolu nigba to n dibo lasiko idibo apapọ Nigeria lọdun 2023.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu nigba to n dibo lasiko idibo apapọ Nigeria lọdun 2023.
Ipade akọkọ to ṣe pẹlu igbakeji rẹ atawọn ọmọ igbimọ iṣejọba rẹ ni ilu Ibadan ni oṣu kẹsan an lẹyin to de lati orilẹede Germany

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Ipade akọkọ to ṣe pẹlu igbakeji rẹ atawọn ọmọ igbimọ iṣejọba rẹ ni ilu Ibadan ni oṣu kẹsan an lẹyin to de lati orilẹede Germany
Akeredolu n ki Aarẹ Bọla Tinubu ku oriire lasiko to gba iwe ẹri gẹgẹ bi Aarẹ tuntun ni Ajọ INEC nilu Abuja ni oṣu kẹta ọdun 2023.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu n ki Aarẹ Bọla Tinubu ku oriire lasiko to gba iwe ẹri gẹgẹ bi Aarẹ tuntun ni Ajọ INEC nilu Abuja ni oṣu kẹta ọdun 2023.
Abẹwo ti awọn gomina lẹkun iwọ oorun ṣe sii ni oṣu kẹwaa ọdun 2023 lẹyin to de lati orilẹede Germany nibi to ti lọ gba itọju.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Abẹwo ti awọn gomina lẹkun iwọ oorun ṣe sii ni oṣu kẹwaa ọdun 2023 lẹyin to de lati orilẹede Germany nibi to ti lọ gba itọju.
Gomina Akeredolu lasiko to buwọlu aba iṣuna ipinlẹ Ondo fun ọdun 2023 loṣu kejila ọdun 2022. Aba iṣuna yii ni eyi to buwọlu gbẹyin gẹgẹbi gomina.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Gomina Akeredolu lasiko to buwọlu aba iṣuna ipinlẹ Ondo fun ọdun 2023 loṣu kejila ọdun 2022. Aba iṣuna yii ni eyi to buwọlu gbẹyin gẹgẹbi gomina.
Akeredolu n fọwọ si iwe ofin idasilẹ awọn ẹkun ijọba ibilẹ mẹtalelọgbọn tuntun ni ipinlẹ Ondo ni oṣu kẹsan an ọdun 2023. Eyi ni ofin to fi ọwọ si gbẹyin gẹgẹ bii gomina ipinlẹ Ondo.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu n fọwọ si iwe ofin idasilẹ awọn ẹkun ijọba ibilẹ mẹtalelọgbọn tuntun ni ipinlẹ Ondo ni oṣu kẹsan an ọdun 2023. Eyi ni ofin to fi ọwọ si gbẹyin gẹgẹ bii gomina ipinlẹ Ondo.
Gomina Akeredolu lasiko ipolongo ibo fun saa keji loye gẹgẹ bi gomina ipinlẹ Ondo.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Gomina Akeredolu lasiko ipolongo ibo fun saa keji loye gẹgẹ bi gomina ipinlẹ Ondo.
 Akeredolu ati iya rẹ.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu ati iya rẹ.
Loṣu kẹsan an ọdun 2022 lo kede iku iya rẹ lori ayelujara.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Loṣu kẹsan an ọdun 2022 lo kede iku iya rẹ lori ayelujara.
Akeredolu ati iyawo rẹ Betty lasiko ajọyọ igbeyawo wọn.

Oríṣun àwòrán, x/Arakunrin Akeredolu

Àkọlé àwòrán, Akeredolu ati iyawo rẹ Betty lasiko ajọyọ igbeyawo wọn.