Kò sí nǹkan tó ṣe ọpọlọ mi - Joe Biden

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Aarẹ orilẹede Amẹrika Joe Biden ti binu bu ẹnu atẹlu iwadii kan to sọ pe o se awọn asiri nla kan mọkumọku ati o n gbagbe lati ranti awọn nnkan.
Ninu ọrọ to ba awọn akọroyin sọ ni irọlẹ Ọjọbọ, ọjọ kẹjo oṣu keji, Biden tẹnu mọ pe. “Ko si nkankan to mu ọpọlọ mi.”
O ni iroyin ofege ni iroyin to ni lati igba ti ọmọ rẹ ti jade laye lo ti n tiraka lati ranti nkan.
“Bawo lo se hu iru nnkan bayii jade?”
Agbẹjọro ẹka idajọ, Robert Hur lo ipinnu pe ki Biden ma se itọju awọn iwe to dirọ mọ ileeṣẹ ologun ati idunadura Afbghanistan lasiko to jẹ igbakeji Aarẹ
Iwadii naa ni Aarẹ ni isoro lati ranti nnkan
Nigba to n ba awọn akọroyin sọrọ, Job Biden ni inu ko dun si iwe ti wọn gbe sita yii nitori ko bojumu.
“Nigba ti wọn ba bimi ni ibeere yii, mo ma ro pe ko si nnkan to kan wọn nibẹ
“N ko nilo ẹnikẹni lati ran mi leti igba ti o [Beau Biden] ku.
Biden ni isẹ ilu pọ ni ọwọ oun ti oun ko si















