You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ọdun Bọ̀ọ̀lì wáyé, wo bí Ẹja, iṣu sísun, ata elépo rẹ́dẹ́rẹ́dẹ́ ti ń ṣe kámi-kàmi-kámi
Ajọdun Ọgẹdẹ agbaagba sisun ti wa di itẹwọgba ati ilumọka bayii lorilẹede Naijiria pẹlu bi wọn ṣe ṣe ajọdun ti ọdun yii ni ara ọtọ.
Ṣe ni gbogbo nnkan jijẹ n ṣe kami kami kami, ti wọn si n ṣe ajọyọ jijẹ bọọli pẹlu awọn ẹja to n fi ogo fun Ọlọrun.
Ko si agbegbe kankan nilu PortHarcourt ti ẹ wọ, ti ẹ ko ti ni ri apapọ Bọọli, iṣu tabi anamọ sisun, ẹja yiyan, dindin ati ata to ta sansan.
Eyi lo si faa to se jẹ pe ilu yii ni ajọdun ọhun ti waye.
Ẹ foju lounjẹ wo lara awọn aworan ohun to n pe ara wọn ranṣẹ nibi Ọdun Bọọli ti ọdun 2022.