Eyi lo si faa to se jẹ pe ilu yii ni ajọdun ọhun ti waye.
Ẹ foju lounjẹ wo lara awọn aworan ohun to n pe ara wọn ranṣẹ nibi Ọdun Bọọli ti ọdun 2022.
Àkọlé àwòrán, Ṣe ni oriṣiriṣi ẹja olorukọ n yọju jade ti wọn ti gba ina sara to mu wọn gbẹ tọọli pẹlu ata, alubọsa ati timaati ti wọn to sara fi ṣara rindin
Àkọlé àwòrán, Ajọdun Bọọli ọlọdọọdun yii maa n waye lati ṣe ajọyọ ounjẹ kan to gbayi ni ipinlẹ Rivers.
Àkọlé àwòrán, Gẹgẹ bi awọn eeyan Pitakwa ni PortHarcourt ṣe gbagbọ, bi o ba ṣe ibẹwo si PortHarcourt ti o ko tọ ounjẹ to gbayi yii wo, o ko ti de ilu rara.
Àkọlé àwòrán, Bọọli tun maa n kọwọ rin pẹlu awọn nkan bii iṣu tabi anamọ sisun
Àkọlé àwòrán, Ọrẹ Bọọli ree o ni PortHarcourt. Lai tii si eyi, igbadun yin o tii pe rara.
Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan to lọ tẹ ara wọn si faaji nibi Ọdun Bọọli