Lasisi Jasper: Wo ìtàn ayé ọ̀gọ́ àgbà iléẹ̀kọ́ Adeniran Memorial ni Ogbomoso
Makinde ko fi ipo to tọ si awa akanda ẹda dun wa nipinlẹ Oyo- Ogbeni Jasper Lasisi
Bi ori ba ṣe dani ati ohun to ba ṣẹlẹ si ni ninu irinajo ẹd alaye lo yẹ ki eeyan gba kadara sí.
Ogbeni Lasisi Jasper ṣalaye pe a ko bi oun ni afọju ati pe iṣẹle kan lo ṣẹlẹ ni Ghana to mu ipenija oju de ba oun.
- Ẹran màálù N328 bilionu ni àwọn ará Eko ń jẹ ní àárín ọdún kan- ìjọba
- Àwọn ọ̀dọ́ dáná sun ilé mẹ́fà, ṣọ́ọ́bù méje ní Bauchi nítórí obìnrin tí wọ́n ló bú Ànọ́bì lórí Whatsapp
- Wo ohun tí iléeṣẹ́ ológun ṣe fun obìnrin yìí lẹ́yìn ọdún Mẹ́tàdínlọ́gọ́rin tí wọ́n gba àkàrà òyìnbó lọ́wọ́ rẹ̀
- Fífẹ̀ ju ìyàwó kan lọ ni àṣírí ẹ̀mí gígùn'
- Ọmọ ìyá méjì ni a pàdánù láàrin ọjọ́ mẹ́ta, ọ̀rọ̀ Dayo nílò ìwádìí, ẹ dẹ́kun isọkúsọ- ẹbí akẹ́kọ̀ọ́ Poly
- Òkú mẹ́ta, alàyè márùn-ún lá ti yọ nínú ilé tó wó ní Lagos Island
- "Ogun ló gbé mi lọ sí Central African Republic, àmọ́ ọmọ ni mo gbé bọ̀"
Ogbeni Jasper salaye awọn ipenija to ni ko to kawe.
Ati awọn oun ti oju ri to ko to bẹrẹ iṣẹ olukọ pẹlu awọn aṣeyori to ti ṣe lẹnu iṣẹ oluko ko to di olori ile ẹko girama Adeniran Memorial Grammar School Ogbomoso.

Arabinrin Deborah Jasper to jẹ aya Ogbeni Lasisi Jasper naa ba BBC sọrọ.
O salaye awọn ipenija to le koju ioyawo akanda ẹda ati awọn iriri rẹ ati bo ṣe kogo ja nipa wọn.
Bakan naa lo gbamọran pe ki wọn ma deyesi akanda ẹda mọ nitori ọpọ ninu wọn n se rere ninu ile ati ni awujọ pẹlu apẹrẹ awọn ohun ti olowo ori rẹ n gbe ṣe ninu ile.
- Ọmọ ìyá méjì ni a pàdánù láàrin ọjọ́ mẹ́ta, ọ̀rọ̀ Dayo nílò ìwádìí, ẹ dẹ́kun isọkúsọ- ẹbí akẹ́kọ̀ọ́ Poly
- Nígbà tí rẹ́kọ́ọ̀dù mí lókìkí kárí ayé, ẹ̀rù bà mí, mo ń ròó pé ọjọ́ ikú mi ti dé ni - Musiliu Haruna Isola
- Ìwà ẹranko làwọn ọmọ tó pa Deborah ní Sokoto hù! Tá ò bá bá wọn sọ̀rọ̀, ó burú - Òṣèré Sokoti
- Ìjòba Oyo ló bẹ̀ mí láti fááyé gba fún Oba Lamidi Adeyemi ní 1971- Omooba Tijani Olawoyin Atiba
- Kò ni mí lára láti dá 'laptop' àti àwọn ẹ̀rù tó kù tí èrò mi gbàgbé padà nítorí pé wọn kò fí òlé kọ́ mi- Mathew Okotie
- 'Ọ̀pọ̀ ìgbà l'èmí gan fẹ́ du àwọn ipò òṣèlú kan lọ́dún 2015, 2019, àmọ́ mo tẹ 'slow' torí bàbà mi, Akala náà ń jáde'