Ooni Of Ife marriage drama:: Ta ni Ashley Folasade Adegoke ti ayé ń pariwo pé òun ni Olorì tó máa rọ́pò Naomi Silekunola?

Oríṣun àwòrán, @Ashleyadegoke
Ni ana, ọjọ kétalelogun, oṣu kejila, ọdun 2021 ni Olori silekunola Naomi to jẹ aya Oonirisa Ogunwusi fi soju opo ayelujara rẹ pe o to gẹOlòrì Silekunola Naomi Ogunwusi: Mo ti sún síwájú, mo gbìyànjú pé kí ìgbèyàwó yìí ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n....
Iya Tadenikawo sọrọ ilẹ kun lori ohun ti oju rẹ n ri laafin Oba Adeyeye Ogunwusi ni Ile Ife laarin ọdun mẹta ti wọn fi ṣe igbeyawo gẹgẹ bii tọkọtaya.
Leyin eyi ni iroyin jade lori ayelujara pe arabinrin kan ti wọn pe ni Ashley Folasade Adegoke ni kabiesi fẹ fi rọpo Olori Naomi laafin.
Ọpọ ni bi Naomi ṣe n bọ sita naa ni Ashley a ko wọle ki aafin ma baa gbofo.
- Àìsàn tó ń ṣe ọ ní ohun ṣe pẹlú oorun rẹ - Onímọ
- Kí ló dé tí Ooni Ile Ife fẹ́ gbẹ̀mí ara rẹ̀?
- Ìjọba àpapọ̀ kéde ọjọ́ Aje àti ọjọ́ Iṣẹgun tó ń bọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ìsinmi ọdún Keresimesi
- Àìsàn tó ń ṣe ọ ní ohun ṣe pẹlú oorun rẹ - Onímọ
- Kí ló dé tí Hisbah Kano ṣe fìwé pe Òbí Shatu Garko tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jẹ 'Miss Nigeria'?
Saaju ni Ashley Adegoke to jẹ alakoso ileeṣẹ ti kii ṣe tijọba Ashley Adegoke Foundation ti ki Oba Oonirisa lasiko to n ṣe ọdun mẹfa lori apere awọn Baba rẹ lọna ara ọtọ.
Nibi to ti n ki Ooni ku oriire lo ti ki Kabiesi pẹlu awọn oriki to kọja bẹẹ.
Omo Ajinaja Ogun. Akande Mii Ajiwe Fun'Osha, Okirikiribiti, Dagunduro Oko ODU… Iti Omo Irumole, Ekun ton fin tori tori, Ekun ton fin tiru tiru, Adigimala awo funfun
This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post
- Alaafin ìlú Oyo gba adé lórí babalawo tó pe ara rẹ lọ́ba, ó fi adé náà kọ́ igi
- Ìjọba àpapọ̀ kéde ọjọ́ Aje àti ọjọ́ Iṣẹgun tó ń bọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ìsinmi ọdún Keresimesi
- Ẹgbẹ́ àwọn olùgbé Magodo Phase 2 gbé kọ́kọ́rọ́ sẹ́nu ọ̀nà iléègbé náà nítorí àwọn ọmọ onílẹ̀
- $5.8bn tí Nàìjíríà tún fẹ́ yá, SERAP ní kí Buhari dẹ́kun owó yíyá
- Kí ló dé tí Hisbah Kano ṣe fìwé pe Òbí Shatu Garko tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jẹ 'Miss Nigeria'?
Ta ni Ashley Adegoke?
Ashley Adekgoke jẹ ọmọ bibi ilu Ile Ife ni ipinlẹ Osun nibi ti ojumọ ti n mọ waye.
Apeje oruko re ni Ashley Folasade Folakemi Adegoke.
O wa lati ile ọla ti wọn ti n jọba ti wọn pe ni Lafogidan ni agboole Adeagba ni Ile Ife
Ashley jẹ Akọṣẹmọṣẹ isiro owo.
Ilu Oba United Kingdom lo gbe fun ọpọlọpọ ọdun.
Oun ni alakoso ileeṣẹ alaanu Ashley Adegoke Foundation.
Folasade maa n saaba pe ara rẹ ni Aya Oosha.















