Tokyo 2020: Wo tábìlì ìṣirò Olympic tó kọjá àtàwọn orílẹ̀èdè tó ti gba àmì ẹ̀yẹ láti ọdún 2000

Oríṣun àwòrán, Olympics.Com
Ere idaraya Olympic to waye nilu Tokyo lorilẹede Japan bẹrẹ ni ọjọ Ẹti, ọjọ Kẹtalelogun osu Keje ọdun 2021, to si pari ni ọjọ Aiku, ọjọ Kẹjọ osu kẹjọ ọdun 2021.
Ọpọ orilẹede lo gba oniruuru ami ẹyẹ Wura Fadaka ati Baba ninu idije naa.
Koda, orilẹede wa Naijiria gan gba ami ẹyẹ fadaka meji ati Baba kan ninu idije Olympic kan, ta si gbe ipo kẹrinlelaadọta.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Àwọn aráàlú Igboho bẹ̀rẹ̀ ìjà ẹ̀mí fún ìdáǹdè Sunday Igboho
- Agbẹjọ́rò 31 láti ìpínlẹ̀ 21 lápá oke ọya dúró ti Abba Kyari lórí ẹ̀sùn jìbìtì pẹ̀lú Hushpuppi
- Ara àwọn alátìlẹyìn Tinubu láti di ààrẹ kò yá, wọ́n nílò àyẹ̀wò ọpọlọ - Bode George
- Wo owó bodè tó san, tó bá gbé ọkọ̀ kọjá ní márosẹ̀ Nàíjíríà
- Iléeṣẹ ọlọpàá mú ọgá àgbà iléèkó nítorí pé o fipá bá akẹkọọ lò pọ
- Èyí ni ìgbà tó ṣeéṣe kí Twitter padà sẹ́nu iṣẹ́ ní Nàìjíríà
Awọn akojọpọ ree nipa awọn koko ohun to waye ninu idije naa, to fi mọ awọn orilẹede to gba ami ẹyẹ ati awọn oludije wọn.
Bi ikọ kan ti se daadaa si
Bi ikọ kan ti se daadaa si
Bi ikọ kan ti se daadaa si












