Tábìlì àmì ẹ̀yẹ Olympic Tokyo 2020

Idije mẹtalelogun ọtọọtọ ati ifigagbaga ojilelọọdunrun o din ẹyọ kan ni yoo waye ninu idije ere idaraya Olympic fọdun 2020.

Ibudo mejilelogoji kaakiri orilẹede Japan ni awọn idije naa yoo ti maa waye.

Oju opo yii ni yoo maa se afihan tabili ami ẹyẹ ti wọn gba, bẹẹ ni yoo maa gbe esi bi idije naa se n lọ si funra ara rẹ lati se afihan iye ami ẹyẹ Wura, baba ati Idẹ ti ikọ elere idaraya kọọkan gba ninu idije naa.

Ami ẹyẹ akọkọ nireti wa pe wọn yoo fun ẹni to jawe olubori lọjọ Kẹrinlelogun osu Keje ọdun 2021.

Bi ikọ kan ti se daadaa si