TB Joshua's Arigidi-Akoko town: Òkúta tó jábọ́ tí kò pa T.B Joshua ní ìkókó, àwa táa mọ ìt

Àkọlé fídíò, Ó dùn wá gaan pé wọn kò gbé òkú TB Joshua wá sílé, bó ṣe ọgọ́rùn ún ọdún, a ṣì ń retí - Àwọn ìyàwó ilé

Ni ilu ibi Wolii Temitope Joshua to di oloogbe ti wọn si n ṣe eto isinku rẹ lọwọ, awọn ara ile rẹ kan ṣi n sọ pe ko dun mọ awọn bi wọn ko ṣe wa sin oku rẹ sile.

Awọn iyawo ile tilẹ ni awọn gbera lọ si Eko lati lọ bere pe bawo ni eto yoo ṣe jẹ ṣugbọn wọn ko jẹ ki awọn ri iyawo Wolii Joshua.

Amọṣa wọn o ri inu bi, wọn ṣi gbagbọ wipe bi wọn ṣi sin in si ilu eko, bo ba to ọgọrun ọdun, wọn yoo si gbe e wa sile ni ilu ibi rẹ tii ṣe Arigidi-Akoko.