TB Joshua Death: Àwòrán bí ó ṣe ńlọ rèé níbi ìsìnkú TB Joshua lónìí
Akojọpọ aworan re e lati ibi isinku Woli TB Joshua
Àkọlé àwòrán, Temitope Balogun Joshua jẹ oniwaasu ati wolii lorilẹede Naijiria to da Ijọ Synagogue Church of All NationsÀkọlé àwòrán, Ọjọ Kẹfa, Osu Keje, ọdun 2021 ni Woli TB Joshua jade laye ni ẹni ọdun mẹtadinlọgọtaÀkọlé àwòrán, Gbogbo eto lo ti to fun titẹ oku TB Joshua si gbangba fun awọn eniyan lati riÀkọlé àwòrán, An eniyan jankan jankan lo tẹle posi rẹ wọ ile ijọsin Synagogue ti wọn tẹ ẹ siÀkọlé àwòrán, Ọpọ eniyan lo pejọ si ile ijọsin naa lati ṣe ẹyẹ ikẹyin fun.
Oríṣun àwòrán, Emmanuel TV/Facebook
Akojọpọ aworan yii wa lati ileeṣẹ BBC News Yoruba
Awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si
Àkọlé fídíò, 'Ìjámbá Ọ̀kadà ló dédé sọ mi di òdi, ìyàwó tí mo yó ìfẹ́ rẹ̀ náà tún wá jẹ́ odi'