Adejare Adeboye: Olúwa yóò dá gbogbo ohun ta sọnù ní 2020 padà ní ilọ́po méje fún wa
Yoruba ni ohun to ba dara n fẹ adura, bakan naa ni ohun to ba ku diẹ kaato.
Ọpọ Ijakulẹ lọmọ Naijiria ba pade lọdun 2020 to kogba wọle, idi ree ta fi nilo ọpọ adura ninu ọdun tuntun 2021 ta bẹrẹ yii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Bí 2020 ṣe ń lọ sópin, Alapinni Oosa wúre ọdún fún ọmọ Yorùbá
- A ti yí orin ọdún ń lọ sópin sí èdè Igbo àti Hausa - Mama Fasoyin
- Àkójọpọ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó dára àti èyí tó burú tó wáyé ní 2020
- Ẹ wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká ọmọ Nàíjíríà tó jáde láyé lọ́dún 2020
- Wo ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù fóónù tí Whatsapp kò ní bá ṣiṣẹ́ mọ́ lọ́dún 2021
- Ẹ wo àwọn èèkàn eléré ìdárayá tó bá ọdún 2020 lọ
- Àwọn àṣà tó milẹ̀ lọ́dún 2020 pẹ̀lú ìtàn lórí bí wọ́n ṣe jáde
Eyi lo mu ki BBC Yoruba tọ ọkan lara awọn ilumọọka ojisẹ Ọlọrun ni Naijiria, Pasitọ Enoch Adejare Adeboye lọ, pe ko fi ojo adura bẹrẹ ọdun tuntun fun gbogbo wa.
Baba gbadura, ilẹ kun, ẹ wo fidio adura yii, kẹ si maa se amin witiwiti.

