Yomi Fabiyi: Fíìmù ‘Owó orí ẹlẹ́wọ̀n’ jẹ́ ká mọ̀ pé ìgbà ìpọ́njú làá mọ ọ̀rẹ́
Yoruba ni ọwọ epo ni ọmọ araye n ba ni la, wọn kii ba ni la ọwọ ẹjẹ.
Ẹkunrẹrẹ alaye nipa owe yii lo wa ninu sinima tuntun ti Yomi Fabiyi n ya lọwọ, to pe akọle rẹ ni ‘Owo Ori Ẹlẹwọn,”
Nigba ti BBC Yoruba kan si ibi to ti n ya sinima naa, ọpọ awọn akikanju osere la ba ni oko ere naa, ti wsn n sisẹ karakara. Yatọ si Yomi Fabiyi to ni ere, a tun ri Muka Ray, Ronke Odusanya, Adekola Tijani ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Sunday Igboho kàn ń gbé ‘Camera’ lẹ́yìn kiri, kí wọ̀n lè rò pé ó ń jà fún Yorùbá - Gani Adams
- Àjọ EFCC ti mú ọ̀dọ́kùnrin mẹ́wàá lórí ẹ̀sùn jìbìtì lílù lórí ayélujára ní Oyo
- Kíni ó lè mú kí ọmọbìnrin sá kúrò nílé láti ìpínlẹ̀ Plateau lọ sí Ekiti?
- Ọkọ̀ ọ̀fẹ́ ní ọmọ tuntun jòjòlò tí wọ́n bí sínú ọkọ̀ òfurufú yóò máa wọ̀ títí ayé rẹ̀- Egypt Air
- Ẹ lọ ṣí gbogbo ilé ẹ̀kọ́ padà ní Nàíjíríà - Ìjọba àpàpọ̀
- Irọ́ ni o! Ìyàwó Ọ̀ọ̀ni Ogunwusi kò bímọ tuntun
- A kò ṣetán láti fa olùdíje kanṣoṣo kalẹ̀ fún ìbò gómìnà l‘Ondo - Àgbáríjọ ẹgbẹ́ òṣèlú
Nigba to n sọ nipa sinima naa, Yomi Fabiyi ni sinima Owo ori ẹlẹwọn lo n sọ fun wa pe ka mase gbe ara le ọrẹ lasiko ti nnkan n dun fun wa.
O ni igba ipọnju laa mọ ọrẹ, bi oorun si tilẹ mu to, sanmọ dudu diẹ yoo wa.