Iya Jogbo Dead: Ọ̀pọ̀ olólùfẹ́ Emmanuella Pobeni Adepoju kẹ́dùn ikú rẹ̀

Iyajogbo

Oríṣun àwòrán, Twitter

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọ̀pọ̀ olólùfẹ́ olóògbé gbajúgbajà sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lóríi rédíò Max FM, Emmanuella Pobeni Adepoju tí gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ sí iyajogbo ló ti ń fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn lórí ìròyìn ikú rẹ̀,

Iyajogbo jẹ́pè Ọlọ́run lẹ́yìn aiasan ranpẹ pẹ̀lú àìsàn ọkàn.

Awọn eniyan fẹran rẹ nitori o ma n dapara lori redio pẹlu Walepowpow ati Obus lori eto 'Wetin Dey show'.

Iya Jogbo

Oríṣun àwòrán, Facebook

Ọpọ ṣapejuwe Iya Jogbo gẹgẹ bi awokọṣe rere fun awọn ọdọ iwoyi

Awọn miran si gabdura fun ẹbi rẹ ati awọn ọmọ rẹ pe ki Olorun tu wọn ninu.

Iya Jogbo

Oríṣun àwòrán, Facebook

Awọn ololufẹ miran tilẹ sọ wi pe oninuure ni Iyajogbo naa, to jẹ irufẹ eniyan ti a le fi yangan.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Awọn miran ni nitori Iyajogbo ni awọn ti ṣe n gbọ eto ‘Wetin Dey Happen’ lati kekere.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Awọn miran royin ipa ribirbi ti eto rẹ n kọ lọkan awọn to n gbọ ọ

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Ọ̀pọlọpọ awọn ololufẹ rẹ lo n gbadura kí Edumare tẹ́ẹ sí afẹ́fẹ́ rere.

Àkọlé fídíò, Working religious women: Ẹ̀lẹ́hàá kìí ṣe ọ̀lẹ- Aminat Adegoke

Kí ló pa Ìyá Jogbo, gbajúgbajà sọ̀rọ̀-sọ̀rọ̀ orí afẹ́fẹ́?

Emmanuella Pobeni Adepoju dágbere fáyé pé ó dìgbà ó ṣe

Gbajúgbajà sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lóríi rédíò Max FM Emmanuella Pobeni Adepoju tí gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ sí iyajogbo ti papòdà.

Gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà Iléesẹ́ TVC, Andrew Hanlon ṣe sọ nínú Ìkéde rẹ̀, iyajogbo jẹ́pè Ọlọ́run lẹ́yìn tó pàdánù ìjà pẹ̀lú àìsàn ọkàn.

Ìyá Jogbo, ẹni tí Hanlon sọ pé ó bá Iléesẹ́ TVC ṣiṣẹ́ fún bíi ọdún mẹ́wàá, gbajúmọ̀ púpọ̀ lórí ètò kan tó máa ń wáyé lórí Max FM èyí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ''wetindey''.

Àkọlé fídíò, Peters Ijagbemi dá àrá lórí ètò 'Ṣé o láyà' ti BBC Yorùbá lọ̀sẹ̀ yìí