Peters Ijagbemi dá àrá lórí ètò 'Ṣé o láyà' ti BBC Yorùbá lọ̀sẹ̀ yìí

Àkọlé fídíò, Peters Ijagbemi dá àrá lórí ètò 'Ṣé o láyà' ti BBC Yorùbá lọ̀sẹ̀ yìí

Orukọ miran wo ni Yoruba n pe Odidẹrẹ?

Agba lo toro lọ......

Awọn ibeere wọnyii ati omiran ni BBC Yoruba beere lọwọ gbajugbaja oṣere ni, Peters Ijagbemi lori eto 'Se o laya'.

Eto yii la maa n fi beere awọn ibeere lede Yoruba lọwọ awọn oju oge ti igba oju mọ lawujọ.

Pataki eto yii ni ki onikaluku le kọ ẹkọ nipa awọn ede ati aṣa Yoruba to ti n wa si igbagbe lasiko yii.

Peters Ijagbemi gbiyanju ipa rẹ ṣugbọn eyin naa le tun ran an lọwọ ninu awọn ibeere to ku diẹ ko gba.