Chichi Igbo: Ọ̀pọ̀ máa ń rò pé mo ní nǹkan ọkùnrin lábẹ́ torí ìrísí mi jọ ti ọkùnrin
Ọkan lara awọn ọmọ ẹgbẹ agbabọọlu lobinrin fun orilẹede Naijiria, Super Falcons, to ti fẹyin ti ni Chichi Igbo jẹ.
Ọdun mejidinlogun si lo fi gba bọọlu, ko to fẹyin ti
Chichi ni isan, idi ati egungun lile ju awọn ọkunrin miran lọ , ti irisi rẹ ko si yatọ si tawọn ọkunrin amọ obinrin ni.
Nigba to n ba BBC sọrọ lori oju ati ohun ti awọn eeyan awujọ n sọ nipa rẹ, Chichi ni ọpọ eeyan lo ti fi ẹnu pa oun lai tii ku.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
O wa koro oju si awọn ọrọ ibajẹ ti ọpọ eeyan maa n sọ nipa rẹ nitori pe irisi rẹ jọ ti ọkunrin.
O si gba awọn eeyan nimọran lati lati ye pa awọn eeyan nipa ọrọ ti wọn ba kọ lawọn oju opo itakun agbaye.
- Ó ṣeéṣe kí ènìyàn 12,000 máa kú lójoojúmọ́ lẹ́yìn Covid-19
- Orílẹ̀-èdè mẹ́wàá tí ẹgbẹ́ alákatakítí Islamic State n fínna mọ́ ní àgbáyé
- N kò gba ₦4bn lọ́wọ́ Magu, ẹ má ró àjẹbánu mọ́ mi láṣọ - Osinbajo pariwo
- Mi ò tíì gba ìwé ìfitónilétí pé wọ́n fẹ́ yọ mí nípò igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo- Agboola Ajayi