Osogbo Photographer: Adediran rọ àwọn òbí láti jẹ́ kí ọmọ ṣe iṣẹ́ tó bá wù ú
Ori lo mọ isẹ asela, Yooba si ni ori ẹni ki ba ibusun, sebi ko ba tun ibẹ se.
Bẹẹ ni ọrọ ri fun ilumọọka ayaworan kan nilu Osogbo, Beta Adewale Adediran, ẹni to wu awọn obi rẹ ko di dokita onisegun oyinbo amọ to kuna, to si pada di alaseyọri ayaworan.
- Ìtàn Gbọnka àti Timi, akọni méjì tó borí Aláàfin Ṣango
- Òkè Idanre rèé tí odidi ìlú kan ló ń gbé lórí ẹ̀
- Lisabi Agbongbo Akala rèé, ẹni tó fi ìfẹ́, ìṣọ̀kan àti ìrẹ́pọ̀ gba ilẹ̀ Ẹ̀gbá lọ́wọ́ ìmúnisìn
- A jọ ṣe ìyàwó pọ̀, a jọ bímọ ní ọjọ́ kan náà, a tún jọ máa ń ṣàìsàn pọ̀ ni
- Ìyàwó mi fẹ́ràn ìrìnàjò òfurufú ni mo ṣe kọ́ ilé Bàálù yìí fún un
Lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, Adediran ni se ni oun n fidi rẹmi ni kilaasi sayẹnsi ti oun wa, titi ti wọn fi le oun kuro nileewe naa, ti oun si lọ sile ẹkọ miran.
- Wọ́n yìnbọn pa àwọn tó fipá bá ọmọ ọdún 12 lòpọ̀ ní gbangba lẹyin ìdájọ́
- Ajínigbé méjì kàgbákò lásìkò tí wọ́n fẹ́ ẹ́ já ọmọ gbà lọ́wọ́ ìyá rẹ̀ l'Ondo
- Àwọn ǹkan ti ọ̀pọ̀ ko mọ nípa Baba Suwe
- China ṣe àgbéjáde "App" tí ẹ lè fi mọ̀ bóyá ẹ súnmọ́ aláàrùn Coronavirus
- Obìnrin tó rè kọjá lójú pópó ló fà ìjàmbá ọkọ́ Osun
Adediran ni ileewe miran ni oun ti bọ si kilaasi isẹ ọna, ti oun si n se daada, titi ti oun fi di ayaworan, to si rọ awọn obi lati maa gba awọn ọmọ wọn laaye lati se ohunkohun to ba wu wọn, dipo ki wsn maa fi agidi mu wọn lati se ohun tawọn ọmọ ko fẹ.









