Idanre Hills, Ondo: Ogun gan kò láyà láti dédé gun òkè Idanre
Nibi ti oke naa ga de, ibudo isinmi marun tan yan yan. Lara rẹ si ni ibudo isinmi Ọwá ati Dágunró wa
fun gbogbo ẹni to ti n gbọ nipa ori oke Idanre tẹlẹ, akoko to lati moju aje ko onisọ bayii gẹgẹ bi BBC Yoruba yoo ṣe mu yin gun oke yii lọ bọ.


Afi bii igba teeyan n goke re ọrun ni, boo ba ti sọnu tabi ha sinu igi lọna, o pari; koda, oke naa kii ṣe eyi teeyan le ni oun fẹ naro lati maa pọn ọn gun.
O ju igba ọdun ti awọn ara ilu Idanre fi gbe ori oke gogoro naa ki wọn to ko lọ si isalẹ nibi ti wọn ngbe bayii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
