Tunde Kelani: Àwa ọmọ Nàíjíríà kò le è bá òyìnbó mọ́ láéláé nínú sinimá ṣíṣe
Tunde Kelani lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ ninu fidio yii, salaye pe lootọ lo dara kawọn osere tiata maa pa awọn araalu lẹrin, ka da wọn laraya amọ o tun yẹ ki wọn gba ọna miran yọ yatọ si eyi.
Kelani salaye pe oun ati Baba Wande ti pari ija to wa laarin awọn, ti oun si ri baba Wande bii ẹnikan ti Ọlọrun fun lẹbun pupọ lorilẹede yii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
O tun woye pe ko si bi ọmọ Naijiria se lee fi ede elede sọrọ laakaye fun awọn to n wo sinima lai jẹ pe a sọ ede abinibi wọn.









