Ibadan Torture House: Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ

Oríṣun àwòrán, Others
Gomina ipinlẹ Ọyọ, Seyi Makinde ti se abẹwo si ile Ọlọrẹ to wa ni adugbo Ọjọọ nilu Ibadan loni.
Bẹẹ ba gbagbe, ile yii ni ọwọ awọn ọlọpa ti tẹ eeyan mẹrin ti wọn ko awọn eeyan ni igbekun lọjọ Aje.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Mo ti sọ ìran nípa ọkọ aképo tó gbiná ní Onitsha kó tó ṣẹlẹ̀ - Primate Ayodele
- Èdè Gẹ̀ẹ́sì tí pọju nínú tíátà Yorùbá tá n gbé jáde lóde òní - Afeez Ọwọ
- Àwòrán bí ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná ṣe wáyé ní ọja Balogun l‘Eko rèé
- Ibi tí àwọn àwàdà Okunnu ti bẹ̀rẹ̀ rèé
- Ẹ̀yin ọkọ̀ epo tó wà ní Ogere, ẹ kó àásá yín ká leè tún ọ̀nà márosẹ̀ ṣe dé Eko - Ìjọba Àpapọ̀
- Bí ilé alájà mẹ́fà ṣe jóná lọ́jà Balogun, ní alájà méjì míràn tún jóná ní Dosumu l‘Eko
Eeyan okòólénígba àti marùn ún ni wọn tu silẹ ninu ile naa, ti wọn tun n lo bii mọsalasi.
Lasiko to se abẹwo sibi isẹlẹ naa si ni gomina Makinde ti pasẹ pe ki wọn wo Mọsalasi ọhun patapata.

Oríṣun àwòrán, Seyi Makinde
Bakan naa lo tun se abẹwo si ibudo ti wọn ti n se itọju awọn eeyan ti wọn tu silẹ ninu igbekun ni mọsalasi ọhun.









