Balogun Fire: Ibùdó ìtajà tó jóná wà ní 43 Martins street, Lagos Island

Ibudo itaja to jona ni ọja Balogun

Ọwọja ina to waye nile alaja pupọ naa lagbara, to si n jo ranin-ranin.

Ibudo itaja to jona ni ọja Balogun

Pẹlu obitibiti ero to wa ni ọja Balogun, o nira pupọ fun awọn panapana lati de ibi ti ijamba ina naa ti n waye.

Ibudo itaja to jona ni ọja Balogun

Diẹ diẹ, ọwọja ona naa n fẹju si, to si gba gbogbo oke ile naa kan.

Ibudo itaja to jona ni ọja Balogun

Lẹyin o rẹyin, ọkọ panapana raye de ibiti ijamba ina naa ti n waye laarin ero to pọ.

Ibudo itaja to jona ni ọja Balogun
Ibudo itaja to jona ni ọja Balogun
Awọn osisẹ panapana n tiraka lati pa ina to n jo
Ọga agba ajọ LASEMA naa wa nibi isẹlẹ ina to n jo
Irinsẹ alagbara ti awọn panapana lo lati pa ina lọja Balogun
Awọn osisẹ panapana n tiraka lati pa ina to n jo
Awọn