Press freedom: Ohun tó ń fa ojúkòkòrò fún àwọn akọ̀ròyìn nìyìí
Agba ọjẹ akọroyin ni Emmanuel Malagu jẹ, bẹẹ naa si ni, o ti foju wina ọpọlọpọ iriri ti ko ṣee ro tan.
- Njẹ́ o dá ayédèrú ìròyìn mọ̀ tí o bá ri i?
- Àwọn ọlọ́pàá ti sọ̀rọ̀sókè fún Òbí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Fakunle lórí ìṣẹ̀lẹ̀ 'Tear gas' tó wáyé ní Osogbo lánàá
- Njẹ́ o ní ǹkan tí èèyàn lè ṣe tí kò bá fẹ́ bí ọmọ àfín?
- Kí ni ìwọ mọ ''Perfume'' sí lédè Yorùbá
- Iwoye Ketu: Òrìṣà kò faramọ́ ká gbìn àlùbósà tàbí ká ló aburada
Ninu ojo, ninu ẹrun, iṣẹ́ iṣẹ́ ni, bẹẹ ni tawọn oniroyin n ri paapaa ju lọ ni akoko yii to jẹ wi pe laarin iṣẹju aaya ni awọn eniyan fi n ka iroyin bayii.
Lati ọdun 1980 ti Malagu Emmanuel ti bẹrẹ iṣẹ oniroyin, o ni ọ̀rọ̀ pọ ninu iwe kọbọ lo ṣe tẹnu bọ ọ̀rọ̀ pẹlu BBC Yoruba.
- Kà nípa ìròyìn mánigbàgbé tí BBC News Yorùbá ṣe láàárín ọdún kan
- Ìdí tí aáwọ̀ èmi àti Tunde Kelani ṣe dá -Part 2 Ti Oluwa Nile- dúró tí mi ò tún gba owó kankan lára fíìmù náà rèé- Baba Wande
- Ikú bàbá mi lo sọ mí di fẹ́ndọ̀ láti ọdún 1974; mo ṣì ń ta -paper- d'òní àmọ́ ohun tójú mi ń rí ... - Nureni Adesegun
- Ẹ̀yin tẹ́ẹ fẹ́ máa ṣe -prank- pa owó bíi tèmí, ẹ má dán an wòo torí adúrú ìyà tó ń jẹ mi yìí - Trinity guy
- 'Ọdún 500 sẹ́yìn ni ọmọ Ọba Aláàfin Oyo tẹ ìlú Ondo dó'