Fayemi: Ẹ̀sùn àjẹbánu àti lílo owó básubàsu la fi kàn wọn

Oríṣun àwòrán, Twitter
Gomina ipinlẹ Ekiti, Ọmọwe Kayode Fayemi ti fasẹ si pe ki adari fasiti ipinlẹ Ekiti, EKSU, Ọjọgbọn Samuel Oye Bandele.
Awọn miran ti wọn tun jawe lọ gbe ile rẹ fun ni, Adari ile iwosan ẹkọsẹ isegun fasiti naa, KSUTH, Kolawole Ogundipe ati adari ile ẹkọ giga to wa ni Ikẹrẹ-Ekiti, Ọjọgbọn Mojisola Oyaraqua.
Igbimọ majẹ ko bajẹ ni ipinlẹ naa, lasiko ipade wọn ni awọn rọ gomina lati gbe igbese iyọni nipo naa, lẹyin ti wọn se abẹwo si awọn ọgba ile-ẹko giga ọhun ati si awọn ile-isẹ ti ọrọ naa kan.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ẹgbẹ́ alátakò fẹ́ lo Boko Haram láti da ìbò 2019 rú - Lai Muhammed
- Ọlọ́pàá kò tíì fi Dino Melaye sílẹ̀
- Irú àtúntò wo ni àwọn ọmọ Nàìjíríà fẹ́ kó bá FSARS?
- Day 25: Àwọn àkànlò èdè lásìkò ìdìbò #BBCNigeria2019
- ‘Ó yẹ kí Obasanjo ti jẹ asaájú Yorùbá, àmọ́ kò leè jẹ́’
- Ilé ẹjọ́ fún Elzakzaky àti ìyàwó ní ẹ̀tọ́ sí ètò ìwòsàn
- Ẹgbẹ́ òsìsẹ́ NLC ti kọ #27,000 owó osù òsìsẹ́
Ẹsun ajẹbanu ati lilo owo ile iwe basubasu, ni wọn fi kan awọn adari ile iwe giga.









