Feranmi Golden Angel: Láti ìgbà ti mo ti wà ní ọmọ ọdún márùn-ún ni mo ti ń kọrin
Feranmi ní ọ̀pọ̀ ìgbà ni àwọn ènìyàn máa ń fi ojú ọmọ kékeré wo òun tí òun bá dé òde eré.
Aya mi maa n kọkọ ja ti mo ba gba 'microphone' lati kọrin- Feranmi Golden Angel.
Eni ọdun marun un ni Feranmi sọ pe oun ti bẹrẹ si ni kọrin ẹmi nitoripe olori ẹmi ni iya to bi oun naa.
Feranmi ṣalaye bi o ṣe kọ iṣẹ orin kikọ ati ipa ti adura gbigba n ko ni ara oun ati aṣeyọri oun.
O sọ awọn awokọṣẹ bii Sola Allyson, Tope Alabi, Alaseyori, Ooni Ife ati awọn lọbalọba mii ko ninu aye oun.
Bakan naa lo tun sọ nipa awọn idojukọ ti oun ti ri di asiko yii.
- Owolabi Ajasa rèé láì wọ aṣọ Ọlọ́pàá lórí ètò -Ṣóo láyà-, ẹ wo bóyá ó Yorùbá rẹ̀ dájú tàbí ó gbé e gbági
- Ẹni tó jẹ́ bàbá fún mi tí a jọ díje ìbò sílé aṣòfin ìpínlẹ̀ Kwara, gbé mi lọ ilé ẹjọ́ - Rukayat Shittu
- Bí òbí mi kò bá kọ́ mi ní èdè Ekiti, n kò lè di gbajúmọ̀, ẹ kọ́ ọmọ ní èdè abínibí - Goroso Ekiti
- Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC
- "N kò ríran, mo ń lọ ẹ̀rọ ata, ro fùfú lórí ààrò, mó sì ń fi ìpèníjà ojú ṣe àwàdà lórí Tik-Tok"
- "Ó kù díẹ̀ kí ń kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní fásitì, ni mo gbà pé iṣẹ́ atọ́kọ̀ṣe ni màá fi jẹun"
- 'Ẹni tí kó bá wà ní mímọ́ kò lè sin Sango, bí Olúkòsò ṣe máa ń búyọ l'óru láti kọ̀yà f'éèyàn rèé'
- Ó jọ àwọn èèyàn lójú bí mo ṣe ń fi èdè Yorùbá kọ́ -Mathematics- lorí ayélujára - Tísà Hakeem Adeniyan