Lady Mechanic: Ajayi Oluwatosin ní a kò nílò láti ṣe yẹsà fún ẹnikẹ́ni, ká tó débi gíga
Ni ilẹ Yoruba ati ni orilẹede wa Naijiria, awọn isẹ kan wa ti a ti yinnu fawọn ọkunrin tabi fun obinrin.
Iyalẹnu si lo maa n jẹ lati ri awọn akọ to wa nidi isẹ ti a mọ mọ awn abo tabi nida keji bakan naa.
Iru isẹlẹ bẹẹ ni ti ọdọbinrin, akẹkọjade kan, Ajayi Oluwatosin, to yan isẹ atọkọse laayo, eyi ta mọ pe awọn ọkunrin lo maa n se iru isẹ yii.
Nigba to n ba BBC Yoruba sọrọ, Oluwatosin mẹnuba bo se bẹrẹ si ni lọ kọ siẹ naa lasiko to wọle ẹkọ fasiti nipinlẹ Ekiti.
- Àwọn oniròyìn ló tú àṣírí ààbò Prof Peller, tí wọn fi ri pa - Lady Peller
- N kò fẹ́ ṣiṣẹ́ aṣẹ́wó ló mú mi máa wa ọkọ̀ taxi - Obìnrin tó ń wa ọkọ̀ èrò
- 'Àti kékeré ni mo ti ń tẹ̀lé bàbáa mi lọ ibi iṣẹ́ tórí mo fẹ́ mọ iṣẹ́ Mọkálìíkì'
- 'Ìnú mi kìí dùn nígbà tí mo ń ṣiṣẹ́ bánkì àfi ìgbà ti mo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ "mechanic"
- "Àwọn ọkùnrin ń pè mí ní aṣẹ́wò, fẹ́ tì mí sí gọ́tà torí mò ń wa Dáńfó"
- Ọlọ́pàá ti rí àjá méjèèjì Lady Gaga ṣùgbọ́n ẹni tó máa ń kó wọ́n jáde ṣì wà nilé ìwòsàn.
Bakan naa lo sọ iha tawn ọrẹ rẹ kọ si isẹ Mẹko to yan laayo, to si ni wọn maa n fi ba oun dapara ni.
Oluwatosin tun fi kun pe se awọn ọkunrin to ba mọ pe mẹkaliki ni oun, maa n ni irẹwẹsi ọkan nipa isẹ ti oun yan laayo naa.
Oluwatosin wa gba awọn ọdọ akẹẹgbẹ rẹ lọkunrin ati lobinrin nimọran lati mase foju pa isẹ ọwọ rẹ nitori pe atẹlẹwọ ẹni, kii tan ni jẹ.
Bakan naa lo woye pe kii se dandan ki gbogbo ọdọ pinnu lati sisẹ lọọfisi tabi lọ se yẹsa-yẹsa fun ẹnikẹni, ki wọn to debi giga tabi jẹ eeyan laye.
- "Ọ̀pọ̀ ọkùnrin ló ń sá fún mi torí mo jẹ́ oníṣẹ̀ṣẹ àmọ́ torí ẹ̀sìn ìbílẹ̀ ni mo ṣe gba ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́"
- Ìyá arúgbó ẹni ọdún 78 wọ gbaga fẹ́sùn ìdigunjalè
- Ọkùnrin kan dèrò ẹ̀wọ̀n lẹ́yìn tó gùn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lọ́bẹ pa nítorí gbèsè
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá kéde orúkọ àti ojú ọlọ́pàá mẹ́ta tó fi pankẹ́rẹ́ na aráàlú, fi tipá ti obìnrin
- Ṣé lóòótọ́ ní pé arábìnrin tó ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú ajá tí pàdánù ẹ̀mí rẹ̀?



