Paula Gomez: ìwé Akinwumi Isola ti mo kà ni Germany lo ṣi ojú mi sí àṣà Yoruba púpọ̀
Wo bí Oyìnbo tó n fi ayọ̀ ṣe ọdún Sango ni ìlú Oyo ṣe dára láti gbé àṣà Yorùba ga síi.
Omowe Paula Gomez to jẹ ọmọ ilẹ Pọtugii to ti gbe ọpọ orilẹ-ede bii Germany ati France sọ idi to ṣe wa di ara ilu Oyo nipinle Oyo ni Iwo Oorun Guusu Naijiria.
Paula lo je iya Tiago to n fi ede Yoruba daraÓ máa ń dùn mí tí Òbí Yorùbá kò bá kọ́ ọmọ̀ rẹ̀ ní èdè nítorí pé èmi ti fi Yorùbá soriíre púpọ̀- Tiago Òyìnbó
O salaye bi o ṣe ni itaniji lati wa si Naijiria lẹyin to ka awọn iwe Oloogbe Akinwumi Orojide Isola ti wọn tumọ si ede Faranse to si jẹ iwuri fun un.
Paula mẹnuba bi o ṣe pade Alaafin Adeyemi kẹta ni eyi to pada fi Paula jẹ aṣoju aṣa fun alaafin Oyo ki baba to waja.
- Ọdún méjìlá la fi gbé nínú ṣọ́ọ̀bù tí à n wẹ̀ lórí gọ́tà nídájí kí a tó rí àánú gbà- Son of the Prophet
- Iya Ibeji kò rántí ńkankan mọ́, ẹnu ti wọ́ sí ẹgbẹ́ kan- Omo Iya Ibeji ọmọ araye le
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Èmi nipò gómìnà tọ́ sí l‘Ogun, a jọ ṣetò àgbéga ọlọ́pọ̀ ọdún fún ìpínlẹ̀ wa ni - Olùdíje fẹ́gbẹ́ Labour
- 'Ẹ̀rú bà mí lọ́jọ́ tí mo wọ bọ́ọ̀sì dẹ́rẹ́bà ọlọ́wọ́ kan lọ Ilorin', ìrírí àwọn èrò ọkọ̀ rèé
- Ìran ni mo lọ wò lójú agbo àríyá níwájú ilé bàbá mi, tí mo fi pàdé Tinubu - Fashola
- Ṣé lóòótọ́ ní Kayamata jẹ́ àdódùn àti òògùn ìbílẹ̀ tí wọn fi ń so ọkùnrin mọ́lẹ̀?

Onisango to jẹ ojulowo ọmọ Yoruba, Sangowale Ibuowo naa ba BBC Yoruba sọrọ.
O sọ bi ẹsin ajoji ṣe n ṣakoba fun idagbasoke ede ati aṣa Yoruba laisko yii.
O sọ nipa iyatọ to ti de ba aṣa Yoruba ati awon oyinbo nsiyi yatọ si ti atijọ.
Bakan naa ni Paula Gomez sọ ipa iwadii to ti ko lori idagbasoke ede ati aṣa Yoruba.