Kehinde Sogunle: Èmi ni alága ìgbìmọ̀ tó ṣe àgbékalẹ̀ ìlànà ìdàgbàsókè ọlọ́dún 25 fún Ogun
BBC Yorùbá ti bá olùdíje fún ipò gómìnà fẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party, Kehinde Sogunle sọ̀rọ̀.
Lasiko ifọrọwerọ naa, Sogunle ṣàlàyè ọ̀pọ̀ ìrírí tó ní láti tukọ̀ ìpínlẹ̀ Ogun de ebute ogo.
Bakan naa lo mẹnuba ọpọ àfojúsùn to ni eyi ti yoo mu ki igbe aye dẹ awọn eeyan ipinlẹ Ogun lọrun to ba de ipò gómìnà.
- Ọ̀wọ́n èpo àti Náírà tuntun ni wọ́n fẹ́ fi dènà ìbò 2023 - Tinubu
- Òkò ba òǹlàjà lórí lásìkò tò ń la ìja, ikú dé
- Ọwọ́ agbófinró tẹ bàbá tó fipá bá ọmọ rẹ, ọmọ ọdún mọ́kànlá lòpọ̀ nílùú Ibadan
- Bí ìbò 2023 ṣe ṣúnmọ́lé, wo ohun tó yeͅ kó o mòͅ nípa rẹ̀
- Tinubu tún pàdé ìyá arúgbó Kwara tó ń ṣàdúrà fun nínú fídíò kan, ọ̀rọ́ bọ́
Oludije fun ipo gomina fẹgbẹ oselu Labour naa salaye pe oun ni alága ìgbìmọ̀ tó ṣe àgbékalẹ̀ ìlànà ìdàgbàsókè ọlọ́dún mẹẹdọgbọ fún Ogun.
O ni awọn ilana naa, eyi ti yoo mu ipinlẹ Ogun de ipo giga, ni ọpọ gomina to ti tukọ ipinlẹ naa gbe ti sẹgbẹ kan.
Amọ o wa fọwọ sọya pe ti wọn ba yan oun sipo gomina, oun yoo se amulo ilana naa, ti igbe aye yoo si dẹ mutumuwa lọrun.
Bakan naa ni Sogunle se agbeyẹwo ilana isejọ APC nipinlẹ Ogun pẹlu ipo tilẹ wa wa ati ohun tuntun ti yoo se, to ba dori aleefa naa.
- Ìyá-ìyàwó kọ ọkọ sílẹ̀ láti fẹ́ ọkọ-ọmọ rẹ̀ ni ariwo bá ta
- Olùdíje sípò gómìnà lẹ́gbẹ́ òṣèlú PDP jáde láyé
- Ọmoͅ osͅù méͅfà kú lórí èͅsùn pè ìyá rèͅ fun ní òògùn olóró ‘Tramadol’
- -Kí ló dé táwọn òṣèrébìnrin fí ń ṣoríire ju àwa ọkùnrin akẹgbẹ́ wọn lọ--
- Ẹ yé fọ́jú tẹ́ńbẹ́lú àwa ìgbìmọ̀ abẹ́nú fétò ìpolongo ààrẹ Tinubu mọ́ -Alawuje